Upload
maiaerielquison
View
369
Download
19
Embed Size (px)
Citation preview
APOSTILAS DE REZAS NA HORA DO ITEFA!
1 OLODUMARE:
IBA OLODUMARE, OBA AJIKI AJIGE. OGEGE AGBEKIYEGUN OKITIBIRITI OBA TI NAP OJO IKU DA ATERE KAIYE AWUSIKATU OBA A JOKO BIRIKITIKALE, ALABURKUKE AJIMUKUTUWE OGRIBADIGBO OBA TI FI IMOLE SE ASO BORA OLUDARE ATI, OLUFORIJI, ADIMULA OLOFIN AIYE ATI ORUN.
A FUN WEN AKE WEN OWENWEN AKE BI ALA.
ALATE AJIPA OLOFA ORO OB A DEKA DAJO AWOSU SEKAN. OBA AJUWAPE ALABA ALASE LORI OHUN GBOGBO.
ARABA NILA TI NMI IGBO KIJIKIJI.
OYIGIYIGI OBA AKIKU ATI OBA NIGBO, OBA ATENILE FORIGBEDI AWAMARIDI OLUGBHUN MIMO TO ORUN.
ELA FUNFUN GBO O OBA TOTO BI ARO, PAMUPAMU DIGIJIGI EKUN AWON ASEKE.
AWIMAYEHUN OLU IPA OBA AIRI. ARINU RODE OLUMORAN OKAN.
ABOWO GBOGBOGBO TI YO OMO RE, NINU OGIN AIYE ATI ORUN IBA TO TO TO .
ORIKI OLODUMARE:
OLODUMARE MOJILONI MO WO GUN MERIN AYE.
IGUN KINI, IGUN KETA IGUN KERIN OLOJO ONI GBOGBO IRE GBA TIOOBA WA NILE WA FUN MI TEMI, T’ AYA, T’ OMO, T’ EGBE, T’ OGBA .
WA FI YEYE WA KI OF F’ ONA HAN WA.
WA FI ELENI SETEMI.
A LAIYE O ALAIYE O. AFUYEGEGEGE MESEEGBE.
ALUJONU ENIYAN TI NF OWO KOLE.
A NI KOSI IGI MEJI NINU IGBO BI OBI EYITI O BA A YA KO’ A YA BIDUN DUN DUN DUN .
2 ORIKI ELA:
IFA L Ó L ONI, IFA L O L OLA IFA L O L O OTUNLA PELUE E ORUNMILA TO MERIN OSA DAYE IFA RO WA O, ELA RO WA O O. BI O NIBE LAPA OKUN.
KO RO MOO BO. BI O O NI WANRAN OOJUMO.
IFA DI ORUNMILA BI O LO L’ OKO KI O WA LE O BI O LO L’ ODO DI WA LE O, BI O L’ O L’ ODE KI O WA LE O.
MOJU BA O MOJU BA O MOJU BA O ASE ASE ASE.
ORIKI ELA:
ÉLÁ S’ O OGBO S’ OGBO.
ÉLÁ S’ ATO S’ ATO.
Ó F’ ODUNDUN S´ OBA EWE
Ó F´ IROSUN S´OSORUN RÉ ;
Ó F´OKUN S´ OBA OMI.
Ó F´ OSA S´ OSORUN RÉ.
Á-S´ EYIN WA Á S´ EIYN BO.
WON´ N´ ELA Ó S´ AYE RE.
ÉLÁ BINU TA KUN O R´ ÒRUN.
OMO ARÁYÉ WA N´ K´IGBE.
ÈLÀ DÈDÈRÈ L’ O MAA SOCALE WA GBURE.
ÈLÀ DÈDÈRÈ! ÈLÀ HIZO.
ORIKI ELA:
ORUNMILA ELERIMPIN IBIKEJI OLODUMARE AJE JO GUN OBIRITI A PI JO IKU AS.
OLUWA MI AMOMIMOTAN AKO MO OTAN KO SE.
ABA AMO OTAN IBA SE KE.
OLUWA MI OLOWA AIYERE OMO ELESEIN ILE OYIN OMO OL OPE TO S AN AN DOGI DOGI.
OLUEA MI OPOKI A MU IDE S OJU EKAN KO JE.
K EHUN HORA ASAKA AKUNOMO OSO GINNI T APA TI NI EWE NINI
OMO OSO PA DE MOWO PA DWE MESE O MBERRE AT EPA JO
OLUWA MI IGBO OMO IYAN BIRIKITI INU ODO
OMO IGBA TI N SOBE JIAJIA
IKU DUDU AT EWO ORO AJ EPO M APON
AGIRI ILE ILOBON A B A B OLOWA DIWERE M ARAN
OLOWUA MI ATO IBA JAIYE ORO A B IKUJ IGBO OLUWA MI AJIKI OGEGE A GBAYE GUN,
ODUDU TI IDU ORI EMERE OTUN ORI TI KO SAIN SE,
OMO EL EJO TI NRIN ODE WA SAKA SAKA.
ORUNMILA ABORU ORUNMILA ABOYE ORUNMILA ABOSISE.
3 ORIKI ORUNMILA:
IFA OLOKUN ASORO DAYO
ELERIN IIPIN, IBIKEDI OLODUMARE.
ORUNMILA NI BABA WA, O E AWA KO NI OBA MEJI, IFA TO OBA O ORUNMILA NI BABA WA IFA TO OBA O KA MO KA LA O KA MA TETE KU,
AMOLA IFE OWODAYE.
OKUNRIN DUDU OKE IGETI,
OLUWA MI AMO TAN OLUNAAMI OKITIBIRITI
TI NPOJO IKUDA A KO MO O TAN IBA SE ,
A BA MO TAN IBA SE, A BA MO TAN IBA SE.
BARA PETU BABA KEKERE OKE IGETI,
ORI AS TI O FI GBOGBO AYE FI OJU ORORI SI PATAPATA.
A BI ARA ILU BI AJERE,
ORISA TI NGEBE NKAN OLE GUN FA GUNWA OKO OKEKU.
OLOMU NLA A BO NI MA RU BABA ESU ODARA ORI SA TI
NGBA NI L´OWO ENI TI O NI IKA NINU
BABA AKERE FI INU SE OGBON,
OPITAN IFE A FUN NIDA.
A TUN ORI ENI TI KO SUNWON SE,
FONRON OWU KAN SOSO AJE JU OOGUN,
ARA YWORAN NI IBI TI OJU RERE TI IMO WA,
BABA ELEPO PUPO MA JE ADIN.
ONILE ORI OKE TI NI AFOPIN EYE S´AYE S´ORUN IBINI ATO I FI ARA TI BI OKE.
OGEGE AGBE AYE GUN AGIRI ILE IL OGBON,
OMO ADO BABA TI I W EWU OOGUN AJANA ETA TI I NU ORI
EKUN NSE BO SURUSURU.
ORISA KO AJE. OLOJHOBAN A RI APA ERAN SE OGUN,
ASE EYI TI O SORO ISE.
EDU OLOJA ORIBOJO OBA A TUN OMO DA BI EWU,
OKURIN ATO EYIN ERIN NI FIFON
OKITIBIRITI A PA OJO IKU DA.
IKUFORIJI.
OBA OLOFA ASUN L OLA.
ERINTUNDE. OMO EJO MEJI.
AKERE SOGBON.
AKONI L ORAN BI IYEKAN ENI
AFEDEFEYO.
IKU DUDU ATEWO ORO JE PON MA PON, ORO A BA IKU J IGBO
ELEEI IPIN AJE JO GUN
ORUNMILA IFA OLOKUN ASORODAYO.
OLOORERE AIKU JE JOOGUN.
BA MI WO OMO TEMI YE O
AJI PA OJO IKU DA.
ORIKI ORUNMILA:
OLODUMARE MO JI LONI MO WO GUN MERIN AYE.
IGUN KINI IGUN KEJI IGUN KETA IGUN KERIN OLOJO ONI.
GBOGBO IRE GBA WA TI OBA WA NI LE. WA FUN MI TEMI.
T´AYA T´OMO T´OGBE T´OGBA
WA FI YEYE WA. KI O OF F´ONA HAN WA.
WA FI ENI ELENI SE TEMI.
ALAYE O ALAYE O. AFUYEGEGEGE MESEEGBE.
ALUJONU ENIYAN TI NF´OWO KOLE.
A NI KOSI IGI MEJI NINU IGBO BI OBI EITI O BA YA KO YA.
ABIDUN DUN DUN DUN ALAYE O ALAYE O.
IFA WA GBO TEMI, ESU WA GBO TEMI.
JEKI ENI YE MI, JEKI ENI YE MI, JEKI ENI YE MI.
KI OLA SAN MI T’ AYA, T’ OMO, T’ IBI, T’ IRE, LO NIRIN PAPO NI.
ILE AYE. WA JEKI AYE MI. KIOYE MI. ASE
ORIKI ORUNMILA :
ETI NIGBO INXOMO ELA.ETI INFO AWO OMONI PAXA NIFE XETI WERE DJI,
OMO AGBONIREGUN, ORUNMILA TE ETI,
KI O O BORRUN TI UM MA FO,
IFA XETI WERE WERE DJI WERE,
IFA XETI WERE.
KI OGBO MOKAN XETI WERE,
KI OGBO MORE
DJE XETI WERE,
KI OGBO MOKAN XADJAMO
OMO EGUNGUN ONIFE,
TI UM XA MARIWO APA KO
KI UNTO WA LONI
MOTI JUBA AKO DA
MO TI JUBA ASE DA
MO TI JUBA ERIN MI
NILE ADO
ARAGBA LO TU IFE.
GBOGBO IN KAN TI MO
BA SO LONI
KI O LO SILE
ASE, ASE, ASE,
ORIKI ORUNMILA:
ORUNMILA DAKUN DABO,
AKODA KUN DABO KOYE SESE.
ORUNMILA ELERIN IPIN AJE JO GUN.
IBIKEJI OLODUMARE AKOKO OLOKUN ASORO DAIYO.
AJA IKOTO ARA ADO ARA EWI ARA OKETASE ARA OJUMO.
IBITI OJO TI NMI WAYE ARA OKE OGETI OKEJI OJE
ERIN FON O LAGILAGI OKUNRIN TI NMO ARA OGDAN LE ALAKETE PENNEPE.
PARI IPIN OLO TO KAN TOKU L’AYE,
OBA IKU JA GBA OMO RE SILE ODUDU TI NDU OR EMERE,
MA BA JO OTUN ORI TI, KO SUN WON ASE ASE ASE.
ORIKI ORUNMILA:
ORUNMILA BARA AGBONIREGUN,
ADESE OMILESE A MO KU IKUFORIJI OLIJENI,
OBA LOFA ASUNLOLA NINI OMO LONI
OLUBESAN ERIN TUNDE ABIKUDIGBO ALAJOGUN IGBO OBA IGDE,
PARA PETU OPITAN ELUFE AMORANMOWE DA ARA RE ORUNMILA IWO LO O KO OYINBO L ONA,
ODUDU PASA AKI IGBO OGUN I LAJULE ORUN DA ARA ORUNMILA A KI IFAGBA,
MERINDINLOGUN AILE K ASINA
MA J AMA RO LERIN IPIN IBIKEJI EDUMARE FONANHAN NI
ORUNMILA
IBURU IBOYE IBOSE ASE.
ADURA ORUNMILA OLUWA MI AJIKI:
ILA JI ORUNMILA, ILA JI ORUNMILA ILA JI ORUNMILA.
MO JO MO KI ATOLA, MO KI ASULA.
MO KI ASURUNENENE. INA KU KU L AHERE.
ENIA KU KU L ABA ADIFA FUN OGOJO L IMO OGBOJO.
O NI TI AWO YO OGBOJO TI AWO YO OGBOJO.
NJ O LUWA MI MA JIKI TIRE YO O.
AWO AJIKI L’ AWO AJIKI AWO AJIKI L’ AWO AJIKI.
AWO AJIKI, L’ A IPE AWO AJA ALE GBHUN A DA A AWON META NLO BO ORI ELU.
ORI ELU KO GB EBO LOWO WON.
AWO AJIKI L’ AWO AJIKI. AWON AJIKI L AWO AJIKI AWO. AJIKI L AWO AJIKI.
AWO AJIKI LA IPE AWO AJA ALE GHUN.
A DA FUN IKI T’ O ON YIO BO ORI ELU.
YIO GBA IBO L OWO ON.
IKI JI O WEWO FINI.
O WA IMU OBI O NA A SI ORI ELU.
ORI ELU GBA LOWO RE.
ONI LOWO IKI ELEIYNJU EGE L A TO MI IBO E IGBANA NI IKI M’EKU S’ EKUN IGBE.
O M’ OHUN YERE NKORIN WIPE.
GB OBI PA O! A WO AYE GB OBI PA O AWO AYE GBO OBI PA O AWO AYE ASE.
ORIKI ORUNMILA:
ALAPANKO AWO MA JU AWO LO
AWO LE GBAWO MI TORITORI
ODIDERE FO O GORI IROKO
O FI OHUN JO AGOGO LO SE IFA FUN IFAKOREDE
A REMO OLODUMARE OMO ATE ENI TEM KO TO FI
ORI SE AGBEJI ARA.
O NI E BA MI SO FUN ALARA E PO MO RIREO NI E BA MI SO FUN AJERO E PE MO RIRE
IRE TO SOUN IRE DE IRE TO
SONU IRE DE
BI IRE BA WOLE E JE KI A NA SUNRU SI NI INU BA LE LALE JU IRE O WOGBO
AGBO YAYAI ARAIN OMOM NI SUN
MO GO PORO LALEDE OMO WEERE W ABA MI HESAN
OLOGBO JI GOLO AWO AWO LILE AWO
OLONI ADIPON YAYA NI IGODO AWO LO SO OKA AWO LO SE ERE
AWO LO EKUN LANIN AWO MAA REE AWO AWO LILE AWO ASE.
ORIKI ORUNMILA:
ORUNMILA AJAMIRANRA AGBONIRTEGUN IBI KEJI
OLODUMARE ELERIPIN
OMO OPE KAN TI NI SORO DOGI DOGI
ARA ADO ARA EWI ARA IGBAJO ARA IRESI,
ARA IKOLE ARA IGETI ARA OKE ITASE,
ARA IWORAN IBI OJUMO TI NMO WAIYE,
AKOKO OLOKUN ORO AJO MA PON,
OLAGO LAGI OKUNRIN TI NMU ARA OGDAN LE,
OBA IKU JÁ GBA OMO E SI LE
ODUDU TI NDU ORI EMERE O TUN ORI TI KO SUNWON SE,
ORUNMILA AJEKI, ORUNMILA AJEKI,
ORUNMILA NI O DI FI ORO RERE L’ O ASE.
ORIKI ORUNMILA:
ORUNMILA MO PE, ORUNMILA MO PE, ORUNMILA MO PE
IFA MO PE, IFA MO PE, IFA MO PE,
ODUDUWA MO PE ODUDUWA MO PE ODUDUWA MO PE.
IGI NLA SUBU WONAKANKAN D’ETU ORUNMILA NI O DI DARAJ
MO NI O DI DARAJI. ASE ASE ASE.
ORIKI DOS OLODUS PARA CONSAGRAÇÃO ORO OPELE E CONSAGRAÇÃO DE ORUNMILA:
EJIOGBE MEJI:
ALELEKUN LOO JE E E OMI NI NKUN
ERIN O SE YI PA DA KUN
ATATA BI AKUN OKUNRIN KUN
KUN KUN LORU
AKO AJA LOLA
AKO AABALA LOSU
OMO ABOKUN
OMO ENI WON ABOYINDE
OMO ENI OSE DI JE LEKE
KAFI LEKE SI TO MO
ELOMIN
OMO ENI
LOMO ENI JEE
A D’IFA FUN ORI DESE PUPA
TOKE APA
TITIKU TARUN NKALE RE RE
AJOGUN GBOGBO NKALE RE
NI LILO NI LILO
ONIKUN NA SO NI BO DEDE PA
ASENIA MO, ASNIA MO
KI ARUN MA SE ONIBODE SE
ASENIA MO ASENIA MO
ASENIA MO
ASENIA MO.
ODU OYEKU MEJI:
AGBA YEKU YEKU ORI GBA
IGBA OWO AGBA YEKETE OSO KALE
ADIFA FUN OLOMO AWAIYE KU
WON NI O RUBO AIKU KO SE POPA
OGUN ODUN ONIO
OKENBE LAIKU GBOIN GBOIN
GBOIN GBOIN NI TOKE
OKE OKE GBOIN GBOIN
IGBA ODU ONIO
OKENBE LAIKU GBOIN GBOIN
GBOIN GBOIN NITOKE
OKE OKE GBOIN GBOIN
IGBA GBOGBO OKENBE LAIKU GBOIN GBOIN
GBOIN GBOIN NITOKE
OKE OKE GBOIN GBOIN
ODU IWORI MEJI:
IWORI MEJI KO BAKUN KO BA WA SE
PA BI O SE DA OSE DA LAWO WON LODE TORI
AKATANPO JAKUN ODO RIRI KALE
ADIFA FUN ORUNMILA
IFA LO NTAIYE OLUFE ORUN SOYE ENI TI SOGBA
TA NI IYO WA BA WA TAIYE WA WON IY SO
EWE ODEDE TI LEE SO
ORUNMILA NI OBAWA TAIYE WA WON YI SO
EWE ORERE TI LEE SO
BA RA PETU NI YIO BA WA TAIYE WA WON YI SO
EWE OPEPE TI LEE SO
ODU ODI MEJI:
ODI MEJI KODA KUN KO BA WA SE
ODI MEJI DIMA IKU DIMA ARUN
ODI MA KURU KURU WALE
OSA ABADA OYE BATA
SAKI NI O TORUN GBO BOROBORO
AFEWO ORUN DIFA,
NI AS AWO OSAIN NI KARO
AGBOFA ATAN GIRIGRI
TI MOMI OJU SOGBERE IRE GBOGBO
OTA BA WA KOWA A TAWA JO
ATAN GIRIGIRI BA WA ATAWA JO
OKE NI KO IWA EBE JO
OBA BA WA KOWA A TAWAJO
ATAN GIRIGIRI
BA WA KOWA A TAWA JO
ODU IROSUN MEJI:
IFA KODAKUN KODABO KOFIYEDENU
IROSU MEJI KODAKUN KO BA WA SE
IBA BURU NA LAWO IBA BURU
IBA BURU NA LAWO IBA BURU
IBA BURU LAWO IIBARAKATA
ADIFA FUN IIGBA
NIJOTI IGBA TO FI NS AWO RODE OYO0
IGBA
OYO NILE O IGBA
EMI LEEE WA DOKO
IGBA MO SEBO OLA TUTU IGBA
MO SEBO OLA TUTU IGBA
MO SEBO OSUN TUTU
MO WA UM GBERIGI ALO TAN ARA TU MI NININI
ODU OWORIN MEJI:
IFA KO DA KUN KODABO KOFIEDENU
OWORIN MEJI KO DA KUN KOBASE
OWON OWO ANNAWO
OWON OMI ANDESUN
OWON ONIJE NI LA NPE NIRIYAN
ADI AFUN YO WON
TI NSOMO OBA LEYO ADUN NI OBA
AJODA EEMI IGBA ARA
OBA AJESE YOKUN TOOTOO LEYO
ONI E SURE WA KE WA RAJA
OOMO OBA ENYIN EGBO OSESE WA
KE WA ROHON YOWON
ESURE WAO E WA RAJA OMO OBA
ODU OBARA MEJI:
ISE OSOHUN AMUSIE
IYA OSOHUN AMO S’AWODA
A DIFA FUN EJI OBARA
TI NRA AGBON OLA
TI ABOGBA ARAIYE NRI ELEGDE MEREE
ELEGEDEE MEREE
EJI OBARA KI NLOTA
KI NLOTA TOOFI DA LAIYE
ELEGEDE MEREE.
ODU OKARAN MEJI:
OYA NI OSA A RA
KURU KURU OTA MANA MANA
AKO APARO
ABA APARO
WON LAABE LORI SAI SAN
LO DIFAFUN OLOFIN, OLOFIN NROTE
WON NI O GBODO KUTE ONASE
AYA RE NSOJOJO ARUN
WON NI O GBODO KU ARUN
OKAN BI OMO RE NI SO REGDE
WON NI E E FOREGDE KU
ONI DUDU GBA DUDU
ONI PUPA GBA PUPA
ALAYIRIN GBA AYIRIN
BARA PETU OBA MAMA KOKU O KARUN
BARA PETU
ODU OGUNDA MEJI:OGUNDA MEJI AWO BOM
LO DIFAFUN BON
NIGBATI NIFI NJE NI ROPO OTA
ENU TI IBON FI NFOHUN
LOFI ISEGUN EROPO EROOFA
E WA BA WA ISEGUN
ARUISEGUN LAA BA NI LESE OBA ORISA
ODU OSA MEJI:
OSA MEJI KODAKUN KOBA WA SE
OSA MEJI LA KOJA
OOGUN YANKAN YANKAN LOJU OPON
ADIFA FUN OLUBAMBI OLUKOSO LALU
OMO ARIGBA OTA ISEGUN
NIGBA TI SANGO NFE NI BE LARIN OSIRI
TI OLUBAMBI TOFI NBE LARIN OTAA AIYE
NJE LARIRA FI SETE
LIGB OTA
LIGBOTA LARIRA FI SETE
LIGBOTA.
ODU IKA MEJI:
IKA MEJI KODA KUN KO BA WA SE
BA FADAKA
BA PADAKA
ADAKA
OOSALA NLO MASO AKADAKA
AKARA KARA OJU KANGANRAN
OKANJO ENIA DAWOJO WOKE
YANYAN EJO NI O OKOMO TIE
LEHIN YO YO YO MAJE
KANO OKO
ADIA DUN ALAYINRIN OKEPE
NIGBATI NFE NJE NIROGBUN OTA
ONI LAO PA YI NRIN
OLALAO PA YI NRIN
ENIKAN O LEE PA YI NRI MA O
TITUN LA TA YI NRIN SE
AYINRIN MAMO DE ARA OODE IWOYA
ODARA OODE IWOYA
ARA OODE LWOYA
ONI LAOO PA YI NRIN
OLALAOO PA YI NRIN
ENI KAN O LEE PA YI NRIN
ENIKAN O LEE PA YI NRIN MOO
TITUN LA TA YI NRIN SE
AYINRIN MAMA DE
ARA ODE LWOYA
ODU OTUROPON MEJI:
OTURUPON MEJI
ANI OSOHUN TO DOA
ADIFA FUN GANNI GANNI
OKE EYO TI O MA SOWO EGAN
KIRI KARI AIYE
AWA MAMA LOWO KEE MA YAN WA O
GANNIGANNI
EGAN O POYN MA DUN
GANNI GANNI MO MO LOWO NLE
EMO GAN MI O
GANNI GANNI
EGAJN O POYIN MA DUN
GANNI GANNI
MO BIMO KUNLE EMO GAN MI
GANNI GANNI
EGAN OPOYIN MADUN
GANNI GANNI
ODU OTURA MEJI:
AGBADA BALE OROKOGO
ITEWU BALE SE SII
ADIFA FUN BABAMALE
BEWO GEREJE TI O MA
FI GBOGBO AIYE SO FE JE
KIN LAJE NI LLARE E WA IFA
ODU IRETE MEJI:
ERUNYAN NFODO KETE
ADIFA FUN ATOKAA
EEYI TI SE LARIO OLODUMARE
LLARI OBA OROKO
EMI IIBA SE ILARI IFA
EMI AAYO SESE
LLARI OOBA OROKO
ERO IPO
ERO OFA
ENYIN OMO PE ILARI IFA
LEMI SE
ODU OSE MEJI
AGBALAKEE LA LE
ADIFA FUN ORUNMILA
IFA OO ISEGUN LAIYE
IFA OO SE TORUN
IFA ISEGUN LAIYE
IFA SE TORUN
ASE KOSI IRONMOLE BII IFA
IFA ISEGUN LAIYE
IFA SE TORUN
KO SI IRUNMIOLE
BII IFA
ODU OFUN MEJI:
IFA NI ADEOWOLE LAWO ALAJIKI
AIYETUTU LOWO AJIWORAN RERE
ADIFA FUN ORUNMILA IFA TOLOREGBE
AIYE TUTU NIYAWO
NJE IJIALO LO REGBE
AIYETUTU NIYAWO
AIYE IFA TUTU OJOMILO O
ONI AIYE IFA TUTU JOMILOOOO
AIYE IFATOTO OJOMILO YIAWO LO OGBE
AIYE IFATOTO NIYAWO AIYE TOTO OJOMILO
ORIKI OLODUMARE, DOS ODUS QUE SE USA PARA CARREGAR EXU E ORIKI DE EXU :
1 OLODUMARE:
IBA OLODUMARE, OBA AJIKI AJIGE. OGEGE AGBEKIYEGUN OKITIBIRITI OBA TI NAP OJO IKU DA ATERE KAIYE AWUSIKATU OBA A JOKO BIRIKITIKALE, ALABURKUKE
AJIMUKUTUWE OGRIBADIGBO OBA TI FI IMOLE SE ASO BORA OLUDARE ATI, OLUFORIJI, ADIMULA OLOFIN AIYE ATI ORUN.
A FUN WEN AKE WEN OWENWEN AKE BI ALA.
ALATE AJIPA OLOFA ORO OB A DEKA DAJO AWOSU SEKAN. OBA AJUWAPE ALABA ALASE LORI OHUN GBOGBO.
ARABA NILA TI NMI IGBO KIJIKIJI.
OYIGIYIGI OBA AKIKU ATI OBA NIGBO, OBA ATENILE FORIGBEDI AWAMARIDI OLUGBHUN MIMO TO ORUN.
ELA FUNFUN GBO O OBA TOTO BI ARO, PAMUPAMU DIGIJIGI EKUN AWON ASEKE.
AWIMAYEHUN OLU IPA OBA AIRI. ARINU RODE OLUMORAN OKAN.
ABOWO GBOGBOGBO TI YO OMO RE, NINU OGIN AIYE ATI ORUN IBA TO TO TO .
ORIKI OLODUMARE:
OLODUMARE MOJILONI MO WO GUN MERIN AYE.
IGUN KINI, IGUN KETA IGUN KERIN OLOJO ONI GBOGBO IRE GBA TIOOBA WA NILE WA FUN MI TEMI, T’ AYA, T’ OMO, T’ EGBE, T’ OGBA .
WA FI YEYE WA KI OF F’ ONA HAN WA.
WA FI ELENI SETEMI.
A LAIYE O ALAIYE O. AFUYEGEGEGE MESEEGBE.
ALUJONU ENIYAN TI NF OWO KOLE.
A NI KOSI IGI MEJI NINU IGBO BI OBI EYITI O BA A YA KO’ A YA BIDUN DUN DUN DUN .
ODUS QUE SE CARREGA ESU:
OSETURA:
OSETURA LADAFUN UNIBATILO LEAJA BENIJO
TETE NO NSJO INDA OIYN AFERE EWEWE
AIYANA DIDE AFERE WEWE AYABA
DIDE AFERE WEWE OSETURA OMI UNROSO ATI ASHA OLODUMARE EBO MORESILE ODARA
ODU OSETURA:
OSETURA AWON ALARA LODIFA FUN ALARA
OMO AMURIN KANDAGBA AGOGO IDE
PSETURA AWO AJERO LODIFA FUN AJERO
OMO OGBOLU KORO IJALE
AJESE OGANNA IMASE
ADIFA FUN OSETERE OMO BUBA OYE OSEKE O JE KOMU
OSE NGBE BO RORUN WAYI IGBA NI OLUO DIDE
OKIKI EBO ASI KANKUN
AWA TETERU KOTETEDA
KEBO WA OTELEDELE OLODUMARE
ODU OSETURA:
OSE OTURA
GBA ERU KI EBO FIN
GBA ERU KI EBO DA
GBA ERU KI EBO D’ODE ORUN DAN DAN DAN
OSETURA TURA TURA TURA
OSE TURA (JUGANDO COM PALAVRAS)
D’IFA FUN APARO YEYE
O NRE OKO ALERO L’ ODUN
IKU KII MO ILE ELEBO
ERO ONAKAN KII I MO ILE APARO
NKAN BURUKU KO NI MO ILE MI
TO NI TI OLUWO
TUFEEEE NI TI JUGBONA ORO TI AWO BA SO S ILE A DI EGUN
D’IFA FUN ARUGBO A BI ETI KOKO O NLO BA WON NA OJA EJIGBOMEKUM
TI OUN ASE L OWO
AKUKO NDA AJA ENI BA TI SUN KO DIDE
ODU OSETURA:
OSETURA LADAFUN ONI BA TILO LEAJA
BENIJO TETE NO NISHO INBA OYIN AFERE WEWE AIYANA DIDE ARERE WEWE
PSETURA OMI UNROSO ATIE ASHA OLODUMARE
EBO MO IRE ODARA
ODU OSETURA:
PENPE LESEE
ELA AGEMO NI O TO GELE
IBA TO GELE
NBA UM RELE LOO WE
AD IFAFUN AWURELA
TI N SAWO RODE IJEBU
APEJIN LAA PE AWURELA
NI JEBU
OSE AWURELE AWO IRE NI O
ORIKI ODU OWORIN SOGBE PARA CARREGAR ESU:
ODU OWORIN SOGBE:
ESU KU ORI EGBA KU ORI
A D’IFA FUN WON NIJESA OMO EKUN
A D’IFA FUN WONNI JESA OMO ERAN
A D’IFA FUN ONI JESA OMO ENI
ALABE MA NRINGBATIE KO MA NYAA LO
OWORIN SOGBE KE ESU EGBA
OWORIN SOGBE KE ESU EGBA
OWORIN SOGBE KE ESU EGBA
ORIKI ODU OWORIN SOGBE:
OWORINSHONGBE TABAKOYU
BAIN IKU BAIN BAIN JOBATI
ADIFA FUN OUN BABALAWO
MERIDILOGUN TINLODIFA
ILE OLOFIN
ORIKI ODU OWORIN SOGBE:
OORE NI IGUN SE
NI IGUN FI PA L ORI
OORE NI AKALA SE
NI AKALA FI YO GEGE L ORUN
IJO MII IJO MII
KI ENI MA SE OORE MIO
D’IFA FUN IJIMERE
TI NLO BA OLOKUN PESAN ODUN
WON NI KO RU BO
OGB EBO O RU
EGBE MI O
PEERE PEKUN OPE
ODU OKARAN SA PARA CARREGAR SEU:
ORIKI ODU OKARAN AS:
OKARAN AS
AWO EJO LO DIFA FEJO
EJO NBE LAARIN OTA NJE ITAKUN LAARIN OTA
NJE ITAKUN LEJO
TI OBA SI ORI
A BA MEJO DI IGI
ITAKUN LEJO
KI ORI GBE WA NIJA
ODU OKARAN SA:
OKARANSA MUKISI BILARI ONE BABALAWO BILORI OMA
BABALAWO LORUN KABOLOSI OBAKARANSA KOSHE SHANDO ELO
ADAMAKOSI BILOR KOGUN GUN GUN ADIFAFUN IKOKO
ODU OKARAN SA:
ALEERE BIDI PETE
A D IFA FUN OWOOMO ASEKU MODI
OSIKALEKA NI NFI OWO OTUN GBE EBO FUNMI NI KI TOSI IGBA MOFI OTUN GBE FUN MOSIFI GBAA
TOBA GORI OPON KOFIN TOBA OWO TOBA KANLE TAN ORN ELEBO NI NLO
ODU OKARAN SA:
OKARAN SA
IYA IGBA O LE MO ON WE
KOMO RE O BERI LO
A D IFA FUN TENTERE OPE
TI NLO RERE GBE ELEBO LEKE
NJE BIKU NBO WA
KO GBE ELEBO LEKE
TENTETE OPE GBE ELEBO LEKE
NJE BIKU NBO WA
KO GBE ELEBO TENTERE
OPE
GBE ELEBO LEKE
ORIKI DE ESU NA HORA DO ORO
ORIKI EXU
2 ORIKI ESÚ
Iba Esu Lalu
Esu oga onilu
Etobajaiye eleso ogun
Otili loogun
Aigada eye
Oroko-ni-ojo-ebo-Ie
Esu tabirigbongbon
Abonijawa-kumo
Esu olafe aseni-bani daro
Esu iwo 10 se babalawo
Ojo metadinlogun 10 gbe odo oya
Esu ma se mi omo elemiran ni 0 se
Esu ma se mi lu enia lumi
Esu ki nkan ma se omo mi
Esu ki nkan ma se awon ara ile mi
Ma jeki a ri ija re
Iwo se oba ti won ti yo loye
Iwo se iyawo ti 0 fi ko oko re sile
Esu ma se mi omo elomiran ni 0 se
Iwo se enia to fi binu soku
Iwo se enia to fi ko soda
Esu ma se mi omo elomiran ni 0 se
Ibukun pupo ni emi fe lodo re
Esu iwo ni ilera
Abo igbega ire oro mbe Iowa re
Jowo ki 0 wa fun mi ni nkan wonyi
Esu elegbara gbo mi kiakia
Esu ma se mi omo elomiran ni ki 0 se
Ase ti Eledunmare
Eledunmare Ase
ORIKI ESÚ
ALAKEGUN KÍ RINGUN IERI
OJINLE AERE KÍ RAIE MOKUNTELE
ARINJINA KÍ ROJU RO MO RE TOLÉ
JE KARONÃ KARONÃ GBE TIUA GBO
JE KARONÃ KARONÃ SORO ARA UA
JE KARONÃ KARONÃ GBE TAIE TARA UA
ORUK IFÁ O LAPE ORUKO IFÁ O LAPE
MO GBAIE PEFA E GBA MIO EGBA MILA
AIÊ TOTO O E DARIJU MIO EIN MOPE
KASORIKI IFÁ KASORIKI ÈSÚ
ÈSÚ BURUKU Ô, ÈSÚ ONÃ
ÈSÚ ABENUGAN, ÈSÚ ORITÁ
ORUKO GBOGBO IN MI MOPE LA PEPO
EJE OIE MI O L’ORUKO IYA MI OSORONGÁ
ATOJE NUA TOKAN JE DO
EJÊ OIE MI KALE O
ORIKI ESÚ
ÈSÙ, ÈSÙ ÒDÀRÀ, ÈSÙ, LÁÀLU ÒKIRI ÒKÒ. ÒKÙNRIN ORÍ ITA, A JO
LANGA LANGA LÁÀLU.
A RIN LANGA LANGA LÁÀLU. ODE IBI IJA DE MOLE. IJA NI OTARU BA
D’ELE IFE
TO FI DE OMÓ WON. ORO EXÚ, TO TO TO AKONI. A O FI IDA RE LALE.
ÈSÙ MÀ SE MI O. EXÚ MÀ SE MI O. EXÚ MÀ SE MI O.
OMO ELOMIRAN NI KÍ O SE. PA ADO ASUBI DA. NO ADO ASURE SI WA
ÀSE
ORIKI ESÚ
Exu ota orisa, osetura ni orukobaba mo o.alagogo ija ni
oruko iya npe e,
Exu odara , omokunri idolofin, o Le sonso si ori esse elese
Ko jê ko jê ki eni nje gbe mi, akii lowo lai um ti exu kuro, akii loyo lai um ti exu kuro, asontun se osi lai ni itiju, exu apata somo olomo lenu, o fi okuta dipo yio,
Loogemo orum , nla kalu, paapa – wara , a tuka mase as exu mase mi Omo elomiran ni ose exu laroiye , ase ase
ORIKI ESU
Iba exu odara , a BA ni wa oran ba o ri da , o san sokoto penpe ti nse onibode olorum,
Oba ni ilê ketu,
Alakesi emeren aji e aji e m u, ogun, a lun se , wa se ibini , laguna Jô igbo bi oro
Exu foli Fo o fi oko Fo oju anan re La nyan hamana, ika ko boro boro, ko La ko Ra o ba ona oja ilê su agbo l ara a yaba ma PA mo, abemu, o se firi oko erro oja
Bara fi imu fon awon sebi oko l o si , ero palemo wara wara.
ORIKI ESÚ
Esu eni enire eni enire ki lana koma la eni enire
Enire titi enire dalaku lana cwo lana Omo
Lana alafia fin mi seu mase mi Omo
Eloniran ni 0 se.
ORIKI ESÚ
Iba E§u ogri oko abaneworan ba 0 rida
E§u apatapiti apitipata 0 da okuta si iyo oniyo
E§u ma se mi omo elemirim ni ose.
ORIKI ESÚ
Ojumo ti mo mo PE
E§u odara ranse
Ojumo ti mo mo ki legbara
Ojumo 0 mo fun mi
Ko mure mi ko mi
Oríkì Èsù
Laro ‘yé Alákétu aki Alákétu.
Èsù Alaketu Orí mi ma je nko o. Èsù Alákétu BA
Nse ki imo. Èsù Alákétu k’érù o ba onimimi.
Èsù Alaketu, fun mi ofo ase, mo pèlé òrìsa. Èsù Alaketu alajiki juba.
Àse.
ORIKI ESU YANGI
Èsù, Bàbá Alàsé,
Ki nnkan má se omo mi
Ki nnkan má se aya mi
Àti èmi nàá
Má se mi lu éniyàn, má se énìyàn lu mi
Lànà owó, lànà omo kàn mi o
Èsù má se mí, omo elòmíràn ni o se
Asóro lògo akétèpe lògbó
Òlòrùn máà jé ki arì ìjà Èsù o
Oríkì fún Èsù
Èsù pèlé o, okanamaho, ayanrabata awo he oja oyinsese,
seguri alabaja, olofin apekayu, amonise gun mapo
Nko o
Èsù, ba nse ki imo
Èsù, keru o ba onimimi
Èsù, fun mi ofo ase mo pele Òrìsà
Èsù, alayiki a juba
Àse
ORIKI DOS ODUS QUE CARREGAM ORI:
ODU EDIOGBE MEJI:
ORI KOO DA MI RE
ORISA MA JEE N SOWO ASENU
A D’IFA FUN OKANKAN LENIRUWO IRUNMOLE
NIGBA TI WON N TORUN BO WA ILE AYE
ORI LO KOKO DA ORUNMILA DA SI OKE IGETI
ORI KOO DA MI RE
ORI LO DS OSUN SODE IJUMU
ORI KOO DA MI RE
ORISA MA JEE N SOO ASENU
ORI KOO DA MI RE
ORI LO DA OBATALA SODE IFON
ORI KOO DA MI RE
ORISA MA JEE N SOWO ASENU
OKRI KOO DA MI RE
ORISA MA JEE N SOWO ASENU
ORI KOO DA MI RE
ORI LO DA AWON IYA MI AJE SODE OTA
ORI KOO DA MI RE
ORISA MA JHEE N SOWO ASENU
ORI KOO DA MI RE
ORI LO DA SANGO SODE KOSO
ORI KOO DA MI RE
ORISA MA JEE N SOWO ASENU
ORI KOO DA MI RE
ORI LODA OYA SI ILE IRA
ORI KOO DA MI RE
ORI LO DA OGUN SI IRE
ORI KOO DA MI RE
ORI LO DA ESU SI KETU
ORI KOO DA MI RE
ORISA MA JEE N SOWO ASENU
ORI KOO DA MI RE
ORI LO DA ORISA OKO SI IRAWO AGBA
ORI KOO DA MI RE
ORISA MA JEE N SOWO ASENU
ORI KOO DA MI RE
ORI LO DA EEGU SI ILE JE
ORI KOO DA MI RE
ORISA MA JEE N SOWO ASENU
ORI KOO DA MI RE
ODU OYEKU MEJI:
OYE IHIN
OYE OHUN A D’IFA FUN OLOYE GELE
OMO ORI RERE T N RU BI OSE
KIN LORI RERE TI N RU
OFULEFULE
N LORI N GBEMI DOYE A FII JOBA
OFULEFULE
IWORI MEJI:
ORI SE MI RERE
ORI SE MI RERE
OLUWO IGI MEJE NI N BE LODE ISALOYE
APA N GBOKO
APA N DADE
ORUURU WON A WEWU EJE KANLE GBONGBO GBON
OLOGUNSESE WON A SIN OMO OKUN KANRUN BE RERE
IROKO WON A YABIRA NIBA [
ARIWONYANGUI AWO WON NILE ALADO
ADANLA AWO WON ODE IJESA
KOTO ONA NII S’AWO IMUJIN GBUGBUUNGBU A D’IFA FUN ORUNMILA
NIJOTI TI NSUNKUN OMO LO SII ODE IJESA
NJE OMO NI MO BI TA LARA WA MI
WON UM JE OWA OGA OGEE GBEBU
OMO EPO YEYE
OMO EPO KAN SI SII SI LEYIN TENA
OMO NI MO BI TAN LARA TU MI
WON UM JE OBA OLOOTU IFE RERE OMO NI MO BI TAN LAR AJO
WON UM JE ONIGBAAJO ILOSI
OMO A DISAN MEMU
OMO NI MO BI TAN NI WON MOWOO TA
WON UM JE OLOWO
OMO ARA GEJGEJE
OMO NO MO BI TAN NI WON JELULU TA
WON MU JE ELEJELUU
OMO ARIGBA ELUKUKUU KE ESU
KO SEEYAN TO MO IKE ÉSU BI ELEJELU
ELEJELU PELE O
OMO ARIGBA ELU KUKUU KE ÉSU
IKIN MI AGBOGBO
IKIN MO ABOTO
OPE TEE RE EREKE ADO O
EIRIGI ABOLA
IKIN TEE RE E YI O
ERIGI ABOLA
ODU ODI MEJI:
ODIDI KIRIDI
AWO ORI LO SEFA FUN ORI
ODIDI KIRIDI
AWOO GBOGBO ARA LO SEFA FUN GBOGBO ARA
NIJO TI WON N BO WALE AYE
WON NI WON O KAALE KI WON O SEBO
NIGBA TI APA DE
APA WAA BORI DURO
KEREKERE
ORII MI O SAI DELENI
KEREKERE
NIGBA TI ESSE DE
ESSE WAA BORI DURO
KEREKERE
ORII MI O SAL DELENI
KEREKERE
IROSUN MEJI
OBA OJU
OJU AS BO SINUU KOOKO
OJU BA BUUBU
O BA KOOKO
O SA BO SINU OJU
OJU WA N SE MONPE MONPE
A D IFA FUN EJI IROSUN
NIJO TI N SUNKUUN PE OUN O NIBUDO
WON NI KO KAALE SEBO
INA KU
INA FEERU BOJU
OSUN KU
OSUN FEGUN AALA SILE
EGIN AALA GBOJU OLORUN SABA GEGEEGE
A D’IFA FUN LABAALE
OMO EGBA ALAKE
NIJO TI N FOMI OJU SERAHUN IRE GBOGBO NI NINI
WON NI ORII RE NI KO BO
O SI GBEBO NBE
O RUBO
NJE KIN NI O WAA SO ILÉ DOJA FAWO
SESEEGA
NI O SO ILÉ DOJA FAWO
[SESEEGA
SESEEGA YI O SAI SOJA DILE
ODU OWORIN MEJI:
AHORANGBON LAWO LODE ORE
AHORANGBON LAWO ODE IJESA
AGBA KAN HANRANGBON HANRANGBON LA DE LOKUN MOLE KA TOO JAGUN IGBOHIN AYE LE KOKOOKO
A D’IFA FUN LAWUSI OKOLE
OMO AFIROKO SEHUN EBO
NIJO AYE E RE LE KOKOOKO BI OTA
O BORI BORI
ORII RE PA
NIBI TI GBE N BORI
BEE LORAAN RE O DARA O BOOSA BOOSA TITIITI
IGBA OOSA SI JU
BEE LOROO RE O SUNWON WON
LEEGUN NI KO MOO BO
O BOOGTUN BOOGUN BOOGUN
IBOJI JIN GBURUGUDU
LAWUSI NI HAA EBORA O LE GBE OUN MO
IGBA O SE GBOGBO E TI O GUN
O BA TO AWON BABALAWO E LO
WON NI ORI OLORI NI O BO KAAKIRI
TI ORAAN RE O TI O GUN REGE YOO SI BO ENU ELENU
WON NI KO SE IJE
KO SE IMU
KO SI PE GBOGBO AWON EEYAN JO
ARAYE BA N WURE
OHUN YOOWO TOO BA TORII RE SE KO DARA
ORII LAWUSA BA GBA GBOGBO IWURE YI
NIRE BA DE
NJE ORI LA BA BO
A BA FORISA SILE
JKIN LA N BO NIFE KA TOO BO IKIN
ENU ENIYAN
ODU OBARA MEJI:
EMI LEMI IGODO
AYAN LAYAN IBARA
AWO KOTO KOTO KOTO
OOUN LOJUU MI O TO
A D’IFA FUN AHUN TO TORI IRE GBOGBO DI FA
A D IFA FUN AHUN EYIN TO ORI IRE GBOGBO ADIFA
NJE O MO DO KO AWEDORO
ORI RERE TI AHUN NI O
O MO DOKO AWEDORO
ODU OKARAN MEJI:
AGBELE GBIBO ARAYE O MOO PE SIN EEGUN
GBOGBO ARAYE NI N PE SIN EEGUN
OBA OMINRINNIPASA LORUKO TI AA PE ORUNMILA
OYEKU MEJI LO TE ORUNMILA NIFA
O NI GBOGBO AYE NI N PEE JO SIN ORUNMILA
ATOBA ATIJOYE
GBOGBO O WON NI N FORII BALE FUN IFA
WON N FORI BALEE FUN IKIN
BABA BORI JAJAJIGI LORUKO A PE OSANYIN
IWORI MEJI LOTE OSANYIN NIFA
O NI GBOGBO AYE NI O PEE SIN OSANYIN
GBOGBO AYE NIN NPE E JOO SIN OSANYIN
AFUNKEKE FALA JAYE LORUKO TI A PE ORISA OBATALA
ODI MEJI LO TE OBATALA NIFA
O NI GBOGBO AYE NI O MOOPE JO SIN OBATALA
GBOGBO AYE NI N PEE JO SIN OOSA LLAWE
A JAYE GBINDINGBINDIN MO SAAN KU LORUKO A PE OSUN
IROSUN MEJI TE OSUN IFA
O NI GBOGBO AYE NI O MOO PE SIN OSUN
GBOGBO AYE NI N PEE JO SIN IWO OSUN
AJEJEJE UM JAIGBO LORUKO O A IWO LLEELE
OWONRIN MEJI LO TE ILEELE NIFA
O NI GBOGBO ARAYE NI O MOO PE SIN LLEELE
GBOGBO ARAYE NI N PE SIN LLEELE
SALUJE MO JOMO AWO LORUKO TI AA PE EYIN IYAMI AJE
OBARA MEJI LO TE IYAMI AJE NIFAO NI GBOGBO ARAYE NI O MOO PE SIN EYIN IYAMI AJE
GBOGBO ARAYE NI N PE JO SIN EYIN IYAMI AJE SE KII ALAGBAJA
TE FII ALAALAAGBAJA LORUKO TI A PE SEU ODARA NIFE OOYE
OKANRAN MEJI LO TE IWO SEU ODARA NIFA
O NI GBOGBO AYE NI O MON PE JOO SIN IWO SEU ODARA
IFA O TO GEGE KOMO ARAYE O MOO PEJO WAA SIN MI O
ORI KAN SOSOOSO O TO GEGE
ORUNMILA O TO GEGE
KOMO ARAYE O WAA FI RERE OWOO WON FUN MI
ORI KA SOSOOSO LORUKOO NI
EWE OJUSAAJU LO NI WON O MOO GBE RERE SE ISAAJUU MI
ORI MEJI NI O GBODO SI
ORII TEMI NIKAN SOSO NI KO WA DENI APESIN
ORI KAN SOSOOSO LORUKO NI
IFA O TO GEGEEGE KOO WAA SERE TEMI FUN MI
OGBE MEJEEJO
EYIN LEE PE SIKITI TI E E LA BABALAWO LODE ISALAYE
EYIN LEE PE SIKITI TI E E LA BABALAWO LODE ISALAYE
EYIN LEE PE SIKITI TI E E LA OGBERI LODE ISLAYE
ODU OGUNDA MEJI:
Orunmila lo dodede nibere
Ifa mo ni to lo to alasaan BA oruko
Sango ni oun to alassan BA rokun
Won ni nje boo BA rin titi
Bo o ba burib burin
Bo o ba de koso
Ilee babaa re nko
Bi won BA se gbegiri
Bi won BA roka
Bi won ba bun o lorogbo
Atakuka adiee kan nko
Sango ni bi mo ba ti yp tan
N o pada silee mi ni
Won ni sango o to alassan BA rokun
Orunmila lo dodede nibere
Ifa mo ni ta lo to alasaan BA rokun
Oya ni oun to alasaan BA rokun
Won ni nje to o bar in titi
Bo o ba burin burin
Bo o ba dele ira
Ilee babaa re nko
Bi won BA poda to tobi
Bi won ba fun o ni ikoko egboo kan nko
Oya ni bi mo ba ti yo tan
N o pada silee mi ni
Won ni oya o to alasaan BA rokun
Orunmila lo dodede nibere
Ifa mo ni ta lo to alasaan ba rokun
Oosaala ni oun to alasaan BA rokun
Nje boo bar in titi
Bo o ba burin burin
Bo o ba dele ifon
Ilee baba a re nko
Bi won PA agbebo adie to royin sinu
Bi won ba mu igba igbin
Ti won ti se ni osiki nko
Oosaala ni bi mo BA ti yo tan
N o pada sile e mi ni
Osa meji
Ahoeo lo ni di
Ni n lo ree fihaa jokoo
A d ifa fun molamela
Nijo to loun n loo Ra ore leru
A d ifa fun oge eyi ti won ni o rubo
Ko Le baa ri eru to sunwon Ra
O ba rubo
O ba kori soko eru
O debe lo ori ore
Ore wu u pupo
O bara a
O dele tan ni ore n sise
Ibuu molamela n dun
Oun waa Le bo loko eru
Ni ore naa rubo si
Won ni koun naa o rubo
Won ni ko bo ori e
Ore naa BA rubo
Won ni ko Ru ebiti
Ko sir u agbon meridinlogun
O si sehum o rubo
Won BA gba iyerosun ifa si ebiti ohum
Won ni ko de si eti oko ti n RO won ni nijo ti ebiti ohun BA um ekute
Ojo naa ni o boo loko eru
Ore BA se bee
O de ebiti ohun o to iwon orun meji
Ko um nnkankan
O BA FEE kaaare
Ojo to pinnu PE oun o nii de ebiti ohun
Lojo naa lo PA eku eda
Ekute ohun waa tobi pupo
Sugbon ibi ori ekute ni ebiti um
Ika meji
Aagba
Oun won ni won joo se inu igbo
Ijokun
Oun won ni won joo se ile lodan
Keekee
Oun won ni won joo se oyo ajakaye
A d ifa fun olouweri
Eyi ti won ni o rubo
Ko bori e
Nijo ti b loo gbe oko niyawo
Nje ogbere
Omo oko
Ori lo mo ibi oko n re o
Eni Toto lati BA eni wa nnkan La n PE ri ori
Oturupon meji
Ologbon kan o gbon gbon gbon
Ko ta koko omi meti aso
ENIYAN KAN O MORAN MORAN KO MOYE EEPE ILE
ENIYAN KAN O SI JE ALARINNAKA
KO PE OUN MO IBI ILE GBE PEKUN
A D IFA FUN ORUNMILA
NIJO TI N F OMI OJU S OGBERE OMO
ORUNMILA FEYAWO FEYAWO
OKANKAN O ROMO BI
O SI FI FE WON DORRI MERIDINLOGUN
OUN WAA LE BIMO BAYII
WON NI KI ORUNMILA O RUBO SI ORII RE
WON NI KII SE WORO KASN NI YOO BII PAAPAA
ORUNMILA BA RUBO
ORII RE BA GBE EBO DODO ENI KE JI ORUN
OSU OHUN NI GBOGBO AWON IYAWO ORUNMILA MEREERINDINLOGUN LOYUN
NI WON BA N BIMO
GBOGBO O WON SI JE OKUNRIN
BI AWON ENIYAN O BAA WI
WON A PE ORUNMILA BI OMO
ORUNMILA O PEE IRO O
BABA LOUN BI
OUN O BIMO
DIPO KI WON O MOO PE OMO ALAWO
WON BA N PE BABA ALAWO
BEE NI WON SE N PE GBOGBO AWON OMO NAA NI BABA ALAWO
ORUNMILA LEYIN O MO PE BABA LAA PE KA TOO PE AWO
OTURA MEJIPE KA N GBE NU IGBO RUN TE
ERE GBA BATA GBA RUN OYE
A D IFA FUN ORI OLA
A D IFA FUN ORI ISE
EBO NI WON NI KO SE
ERRO IPO
ERRO OFA
ONI ISE KO MA NPE ORI OLA TI RUBO
IRETE MEJIIWO OTE
EMI OTE
OTE ODE MEJI ODO OTITO
OTE OD EMEJI ODO ODO
A D IFA FUN BABA LORI IRE RE
MAA LE NSE ERERE
IFA JEKI NLORI RERE
KI NSE LESE ERERE
EBO NI WON NI KO SE
O SI GBEBO NBE O RUBO
KO I PE KO I JINA
E WA BA NI JEBUTU IRE GBOGBO
OSE MEJIOSE KETE
O GBOGUBN NLE AYE
O RIN GBAJA
O GBOGBO JI
ORUNMILA LOUN O FI GBOGBO KELEKELE TOUN SERE
A D IFA FUN ORI
NIJO TI NSE OHUN GBOGBO
TI SEU ODARA SI NAA SE IRE E MI O FUN MI
SEU ODARA
SEU ODARA SI NNA SE IRE E MI O FUM MI
SEU ODARA
OFUN MEJIKUDU KUDU KUDU
ADO TORI OOGUN SO
OOGUN OHUN O SI PO
OLOOGUN NI O FOO MU U WA
A D’IFA FUN ORI ORUNMILA
NIGBA TI WON BI ORUNMILA O SE
KO LE BAA ROOKO RERE JE LAYE
ORUNMILA SI DAGBA DIE SAA
O LO TO GEGE KI WON O WA LO REE TA OUN
WON BA GBE ORUNMILA LO SODS OBA ALARA
EJI ASA Omo AMURIKAN DOKAN AGOGO
WON LAWOON FEE TA OJA KAN FUN O
WON LERU KAN NI
O BA BEERE LOWO ORUNMILA PE KINNI ISE TO MOO SE
ORUNMILA LOUN O NISE KAN
BOUN BA TI JI
OUN A WE
OUN O SI KUN
OUN O SI BO SORII OTITA
OUN A SI JOKOO
WON O SI GBE OUNJE WA BA OUN
BOUN BA SI TI JEHUN TA OUN O SI MOO SERE
O TUN DI LOLA
ALARA LOUN O RA MO
ORUNMILA NI WON O MOO GBE OUN LO SODE AJERO
WON TUN DODO OUN NAA WON SALAYE
OUN NAA LOUN O RA
WON BA TUN GBERA O DODO OWARANGUN AGA
ORIKI PARA CONSAGRAÇÃO E REZA DIARIA:
ORIKI ORI:
Òrì mi ò sérere fun mi
Òrì mi ò sérere fun mi
Òrì oka ni sanu oka
Òrì ejo ni sanu ejo
Afo mope ni sanu ope
Òrì mi ò sérere fun mi
ORÍKÌ ORÍ
Bí o bá maa lówó, Bèèrè lówó orí re.
Bí o bá máa sòwò, Bèèrè lówó orí re w o.
Bí o bá máa kolé o, Bèèrè lówó orí re.
Bí o bá máa láya o, Bèèrè lówó orí re wo.
Orí máse pekùn dé. Lódò re ni mi mbò.
Wá sayéè mi di rere. Ase.
ORÍKÌ ORÍ
Orí, pèlé, Atèté níran Atètè gbe ni kòòsà.
Kò sóòsà tíí dá ‘níí gbè léyìn orí eni.
Orí pèlé, Orí àbíyè, eni orí bá gbeboo rè, kó yosèsè.
ORIKI ORI:
IJUBÁ ÒRÌ
O SE, O SE Ô, O SE ÔOSÈ BABÁ WÁO SE, O SE Ô, O SE ÔOSÈ BABA WÁ
ORIKI ORI:
ORI BURUKI WU TUULI A KI I DA CSC ASIWEREE MO LOJE ONA A KI M’ORI OLOYE LAWUJO A DIA FUN MO BOWO TI I SO OBIRIN OGUN ORI TI JUBA LOLA ENI KAN O MO
ORIKI ORI:
ORI LO NDA ENI SEI ONDAYE ORISA LO NPA ENI DA O NPA ORISA DA ORISA LO PA NIDA BI ISU WON SUN AYEMA PA TEMI DA KI ORI MI MA SE ORI KI ORI MI MA GBA ABODI
ORIKI DE EGUNGUN E DOS ODUS QUE CARREGAM EGUNGUN:
Ile mope o o,Akisale mo pe o o,Etigbure mo pe o o, Asa mo pe o o,Eti were ni ti ekute ilê, Asunmaparada ni tigi aja, Emi Omo re ni mo pe o,Jeki nwa laaye,Maa jeki nku,Maa jeki nri ija igbona,Maa jeki nri ija Ogun,Jowo wa jemi loni,Ki o fire fun mi, Ase.
ORIKI EGUN
Too ki odón yii
O rowa ro ese lai si iyonu
Ki o ro wa se owo
Ki o ro wa si omo
Ki o ro wa si alàáfia
Bi bee ba ni
Ki obi o yan o.
ORIKI EGUN
Tó kòrooro orò, en keèré e n awèrè tó kòrooro orò, en keèré e n awèrè làsèsè mojubà awo làsèsè, làsèsè ó món làsèsé mojubà awo làsèsè, làsesè ó món làsèsè olúwa kí a àgbà o
Làsèsè làsèsé ó mòn opé èye ye a ìrokò, olúwa dé a kése, bá àwa kóse
Olúwa dé àse ní koja bàbá ìrokò ká kí s éégun óàwa léébá re
Egun bale egun bale, baba egun ati nlo.
Egun dara egun dara oni se sun egun dara.
ORIKI EGUN
Egungun kiki egungun
Baba egun ranran fè awo ku opipi
O da sobo fun le wo
Baba egun bata bango egun de
Bi aba f’atori na lé egun asède
Oriki para egungun
Eegun mope o Iie mope o Etigbure mope o Eti we niti e kete ilêAsunmanparada niti gi aja Ago kii gbo ekun omore ko man Tati wereEegun abata arago gbaleAroro finju ofofo ayeEgungun abala Omo ayeAra orun kinkinOna mo ni lagba namo nitoAbala peleo oba olomo wa bi koribi
1 reza de egungun
IYA NO FE ELEGUN OJARE
FELEGUN
BODUN BADE MAROMO GBEJO
FELEGUN
BODUN BADE MALERO I EYIN
FELEGUN
OROYI YOODARIWO BEEJE NFELEGUN
2 re za de egungun
OKOKO ADIRE BERE N KOMO YOYO
OKOKO
3 reza de egungun
KULUKULU SE
OJO TI BALUWE SE WOWO
4 re za de egungun
ESA WON LEGBA
OPE TI KOBAYA FEEGUN
ESA WON LEGBA
5 re za de egungun
AWA KIISE ALAKISA TIKO ROWO RASO
ARAN LOKU TAAFI NDA TIWA
6 re za de egungun
EGUNGUN ODUNPE O
EGUNGUN ODUNPE
OLE ATI AKARA
AKARA OLELE LAFI NSORO NIGBALE
EGUNGUN ODUNPE
7 re za de egungun
ENI OJU BANTI KOWOLE
OJU KOTIWA ABA BABA RODE
ENI OJU BANTI KOWOLE
8 re za de egungun
É É É É BABA O BABA O
É É É É BABA O BABA O
É É É É YEYE O YEYE O
É É É É YEYE O YEYE O
BABA SO WA NU AWA O RI MO O
O SO WA NU AWA O RI MO O
YEYE SO WA NU AWA O RI MO O
O SO WA NU AWA O RI MO O
BI MO RI BABA ORO MI A DUN BI OYIN
BI MO RI YOYO ORO MI A DUN BI OYIN
JOUN N GBOGBO ALAPALAOMO A SUS MO SA
JOUN N GBOGBO KO TO BERE KO TO MO BUKA
JOUN N GBOGBON
AWON OMO LA NI WON YI A O MO WON
AWON OMO LA NI WON YI A O MO WON
DIGBOLU KOLU DIGBOLU KOLU
BO O BA DIGBOLU N O PADE TEHIN RE O
DISGOLU KOLU DISBOLU KOLU
IGBA O MO O JO
É É É É TETE NDE KO OO JO O
KO BI ENI RO RO BI ENI KO BE
RO BI ENI KO BE KO BI ENI RO
WA LA WA MO DO ORO AWA M ODO
JO BI AGBEGI JO BI AGBEJI JO
IGBA TI IWO MO O JO O
É É É É TETE NDE
É É É É TETE NDE O
E TUN GBE É É É TETE NDE O
E TUN GBE É É É TETE NDE
É É É É TETE NDE KO OO JO O
BO BA TI DPATI OPONA ATATA
É É É É TETE NDE
É É É É TETE NDE
ORIKI EGUNGUN
EGUNGUN A YE KII
SE BO ORUN MO JUBA RE EGUNGUN MONRIWO ILE MO PE O GBOGO
MONRIWO ILE MO PE O EGUNGUN O A KII DE WA O A KII E EGUNGUN
ILE MO PE O WON GBOGBO ARA ASIWAJU AWO WON GBOGBO
ARAALE ASIWAJU MI GBOGBO MONRIWO ILE MO PO O EGUNGUN O
MO PE GBOGBO ENYIN SI FUN MI AABO ATI IRONLOWO AGO KII
NGBO EKUN OMO RE ILE MO PE O GBOGBO MONRIWO ILE MO PE O
EGUNGUN O KI O MA TA ETI WERE BABA AWA OMO RE NI A NPE O ILE
MO PE O GBOGBO MONRIWO ILE MO PE O EGUNGUN O KI O SARE WA
JE WA O KI O GBO IWURE WA ILE MO PE O GBOGBO MONRIWO ILE
MO PE O EGUNGUN O MA JE A RIKU EWE MA JE A RIJA SEU JE A
RIJA OGUN MA JE A RIJA OMI MA JE A RIJA SOPONNA ILE MO PE O
GBOGBO MONRIWO ILE MO PE O EGUNGUN O MO TUMBA BABA
ILE MO PE O GBOGBO MONRIWO ILE MO PO O EGUNGUN O ILE MO PE
O GBOGBO MONTIWO ILE MO PE O EGUNGUN O EGUNGUN O
EGUNGUN ILE MO PE O EGUNGUN O