Upload
others
View
3
Download
0
Embed Size (px)
Citation preview
A pese re lati owo Ile Ise Eto Inawo, Isuna ati Aato Oro Aje.
Olu Ile Ise Ijoba Ipinle Kogi, Lokoja
ATUNYEWO ETO ISUNA AWA ARAWA IPINLE KOGI FUN ODUN
EGBAA O LE OKOO / OGUN
AKOPO OHUN TO WA NINU IWE YII
Atunyewo Eto Isuna Awa Arawa Ipinle Kogi 1
Ifaara
Iwe to tumo Isuna
Ilana Gbogboogbo
IKADI ISUNA
Nibo ni owo naa yoo ti wa?IKADI AKOJOPO OWO TI IJOBA NGBA
Nibo ni owo naa lo?
02
03-05
06
07
08-09
Bawo ni ijoba yoo se ri eyawo gba?EYAWO ABELE ATI EYAWO OKEERE 10
OWO IFIJINKI ABELE ATI OWO IFIJINKI OKEERE
Bawo ni ijoba yoo se ri owo ifijinki gba?
11-12
Ipin fun ile ise ati eka ijoba to ga ju13-14
AWON AKANSE ISE TO GA JU: ISUNA EGBAA ODUN O LE OKOO / OGUN TI A FOWO SI
15-18
Oro Akoso
Atunyewo Eto Isuna Awa Arawa Ipinle Kogi
Gege bi a ti mo, eto isuna awa
ara wa je jade lati inu eto isuna
gangan. Nitorinaa, eto isuna
awa ara wa fun odun egbaa o le okoo ni
a fayo lati inu eto isuna ti a fowosi fun
odun egbaa o le okoo. Sugbon, ni
lowolowo yii, akude ti ba oro aje
agbaye nitori igbadi arun korona ti a mo
si COVID-19. Latari eyi, owo epo robi
l agbaye t i j aw a s i l e l a t i b i i
e t a d i n l a a d o r i n d o l a s i d o l a
metadinlogun; beeni sise owo dola
gbera so lati oodunrun naira o le marun
si naira kan si otaleloodunrun dola si
naira kan. Eleyi lo mu ki ijoba fi oju
sunnukun woe to isuna naa lati se
atunyewo re.
Awon ijamba ti arun korona ti se ti mu
ki akude ba oro aje ipinle yii ti o si koba
ona lati le pawo wole labele. Ona a ti
pese awon nkan loniruuru paapaa ti di.
Awon osise ijoba, osise banki ati awon
ile ise miran nsise lati ile won. Eleyi kii
se akoko to pani lerin rara. Nitorinaa, a
gbodo gbe awon igbese akin lati rii pe
isele laabi yii ko so oro aje wa di
akurete. Ijoba nwo awon ona miran lati
ri owo fi se ijoba sugbon eyi le pe die.
Ijoba ipinle yii ti wo sakun abayori
igbadi arun korona yii nipase igbimo
teekoto kan, o si wa mu eto ilera, eto
eko, eto ogbin ati awon inawo
atigbadegba lokunkundun.
Nitori idi eyi, ijoba ti din eto isuna odun
e g b a a o l o o k o o s i b i l i o n u
m e j i l e l o g o r u n , m i l i o n u l o n a
etalelogofa, egberun mokanlelaadorun
ati ojileleedegberun o din mesan naira.
Iye ti apapo eto isuna naa je tele ni
bilionu merindinlogosan, milionu lona
etalelogofa, egberun mokanlelaadorun
ati ojileleedegberun o din mesan naira.
Iye ti a yo kuro ninu re je bilionu
merin le laador in ; e ley i je ida
mejilelogoji ninu ogorun. A o tesiwaju
lati maa dahun leye o soka si eto oro aje
latari arun korona lati rii pe alaafia ati
itura ba awon eniyan wa.
ALHAJI YAHAYA BELLO
GOMINA IPINLE
2
Ifaara
Atunyewo Eto Isuna Awa Arawa Ipinle Kogi 3
Ki ni Isuna?
Isuna n se afihan ohun ti ijoba
nreti lati gba gege bi owo to n
wole si apo ijoba; bii owo
atilehin, owo ti a ya; ati pee lo
ni a o fi pamo tabi ya ati ki ni
ijoba nseto lati na owo naa le
lori.
Eto isuna je akosile to nse
apejuwe bi ijoba se n seto lati
na owo ajoni gbogbo ara ilu-
paapaa julo, owo ori. Ijoba
apapo, ijoba ipinle ati ijoba
ibile lo ni eto isuna won labe
ofin.
Ninu ijoba tiwantiwa, gbogbo
omo ilu to duro daadaa lo ni
eto lati mo bi ijoba se n na oro
ajoni ara ilu fun ipese awon
o h u n a m a y e d e r u n f u n
mutunmuwa.ti mo bi ijoba se
n na oro ajoni ara ilu fun ipese
awon ohun amayederun fun
mutunmuwa.
Ki ni Eto Isuna Awa Ara
Wa?
Ki ni Eto Isuna Awa Ara Wa?
Eto isuna awa ara wa je eleyi
to rorun ti ko ni iruju ninu, ti o
si ye gbogbo mutumuwa
yekeyeke. Eto isuna awa ara
wa le je eyi to yato die nipa
ifojusun tabi nipa gigun ati
agbekale re. Sugbon sa, eto
isuna awa ara wa gbodo wa
larowoto gbogbo ara ilu, o si
gbodo wa lori ero ayelujara ti
ijoba.
Apapo Inawo ninu Isuna:
Eleyi ni apapo iye owo ti se
Itupale Awon Oro Ti A Lo Ninu Iwe Eto Isuna Yii
Atunyewo Eto Isuna Awa Arawa Ipinle Kogi 4
agbekale re ninu eto isuna fun
odun kan pato. O je apapo
inawo atigbadegba ati inawo
lori ise idagbasoke gege bi ile
igbimo asofin ipinle ba se
gbaa wole ati gege bi Gomina
Ipinle ba se bu owo luu.
Akojopo Owo Ilu: Akojopo
Owo Ilu je gbogbo owo ti ijoba
gbagbo lati ri gba lowo ara ilu
laariin odun latari owo ori ati
awon eto miran fun ijoba.
Ijoba n gba awon owo wonyii
loruko awon ara ilu lati fi pese
awon ohun amayederun.
Elewo Lori Isuna: Eleyi ni
iyato to wa laarin ohun ti
ijoba lero lati na ati iye to
wole gan an. Elewo lori isuna
a maa waye nigba ti iye ti a ba
fen a bap o ju apapo owo ara
ilu ati owo ifijinki.
Owo Ifijinki / Iranlowo: Owo
iranlowo je okan lara ona ti
ijoba fi n ri owo lati fi se awon
ise akanse fun igbe aye irorun
fun awon ara ilu ati lati fi mu ki
oro aje ilu ru gogo sii. Owo
iranlowo yii le wa lati okeere
tabi ni abele. Owo iranlowo kii
se owo ti ya rara ; nitorinaa,
ijoba ko si labe ofin lati da iru
owo bee pada.
Eyawo : Ona miran ti ijoba n
gba lati fi ri owo bojuto eto
isuna ni eyawo. Ijoba a maa
seto eyawo lati fi bojuto eto
isuna laarin odun nigba ti awon
owo ara ilu ati owo iranlowo ko
ba to lati fi gbo bukata isuna.
Eyawo le wa labele tabi lati ile
okeere. Eyawo le je fun awon
Itupale Awon Oro Ti A Lo Ninu Iwe Eto Isuna Yii
Atunyewo Eto Isuna Awa Arawa Ipinle Kogi
ise akanse tabi fun awon
inawo gbogbogbo.
daadaa lo ni eto lati mo bi
ijoba se n na oro ajoni ara ilu
f u n i p e s e a w o n o h u n
amayederun fun mutunmuwa.
Ki ni Eto Isuna Awa Ara Wa?
Eto isuna awa ara wa je eleyi
to rorun ti ko ni iruju ninu, ti o
si ye gbogbo mutumuwa
yekeyeke. Eto isuna awa ara
wa le je eyi to yato die nipa
ifojusun tabi nipa gigun ati
agbekale re. Sugbon sa, eto
isuna awa ara wa gbodo wa
larowoto gbogbo ara ilu, o si
gbodo wa lori ero ayelujara ti
ijoba.
5
ETO ISUNA LEREFEE
Atunyewo Eto Isuna Awa Arawa Ipinle Kogi
N102.1bnEleyii ni Gbogbo Owo ti Ijoba n sereti lati lo fun isuna.
N91.82bnN10.3bn
BILIONU LONA EJILELOGORUN ATI MILIONU LONA OGORUN
Owo ti ijoba n reti lati gba lowo awon ara ilu ati owo
iranlowo je
BILIONU LONA OKANLELAADORUN O LE MILIONU LONA EJILELOGORUN NAIRA
Elewo lori eto isuna je
BILIONU MEWAA O LE MILIONU LONA
OODUNRUN NAIRA
Isuna ti a fowosiGbogbo Owo ti Ijoba n sereti lati lo fun isuna je: Bilionu lona igba o
din merinlelogun ati milionu lona ogorun naira (N176.1bn)
Owo ti ijoba n reti lati gba lowo awon ara ilu ati owo iranlowo je: Bilionu mokanle laadofa o le milionu lona egbeta naira (N111.6bn).
Elewo lori eto isuna je: Bilionu merinlelogofa o le milionu lona eedegbeta naira (N64.5bn)
7
Atunyewo Eto Isuna Awa Arawa Ipinle Kogi
₦
₦
15.04bn
(ForeignLoans): 2.9bn
(Value Added Tax): 11.8bn
(OtherStatutoryRevenue): 1.77bn
(StatutoryAllocation): 29.19bn
(Domestic Grants): 6.37bn
OpeningBalance 24.42bn
(ForeignGrants): 3.23bn
(DomesticLoans): 5.4bn (Sales of
Govt. Assets): 1.9bn
₦
Isuna ti a fowosi
Internally Generated Revenue - N19.04bnStatutory Allocation - N50.43bnValue Added Tax - N17.5bnOther Statutory Revenue - N3.97bnDomestic Grants - N14.39bn
Foreign Grants - N6.28bnDomestic Loans - N28.47bnForeign Loans - N34.06bnSale of Government Assets - N1.99bn
8
Nibo ni Owo naa Yoo ti Wa?Ikadi Apapo Owo Ara Ilu
Owo Apawole Labele (IGR):
BILIONU MARUNDINLOGUN ATI MILIONU LONA IRINWO
NAIRA
Owo Ipinfunni Labe Ofin
BILIONU MOKANDINLOGBON O LE MILIONU LONA
MOKANDINLOGUN NAIRA
Owo Ori
Awon Oja
BILIONU MOKANLA O
LE EGBERIN MILIONU
NAIRA
Awon Owo Apawole Miran Labe Ofin
BILIONU KAN O LE MILIONU
METADINLOGORIN NAIRA
Owo Iranlowo Labele
BILIONU MEFA O LE MILIONU LONA
METADINLOGOJI NAIRA
Owo Iranlowo Lati Okeere
BILIONU META O LE MILIONU LONA
METALELOGUN NAIRA
Eyawo
Labele
BILIONU MARUN O
LE MILIONU LONA
IRINWO NAIRA
Eyawo Lati
Okeere
BILIONU MEJI O LE MILIONU LONA
EEDEGBERUN NAIRA
Tita Awon Ohun Ini Ijoba
BILIONU KAN O LE MILIONU LONA
EEDEGBERUN NAIRA
Atunyewo Eto Isuna Awa Arawa Ipinle Kogi
N65.53bn
N102.12bn
N36.6bn
Isuna ti a fowosi
Total Recurrent Expenditure - N77.01bnTotal Capital Expenditure - N99.11bn
9
Inawo: Nibo ni Owo Naa N Lo ?
BILIONU LONA EJILELOGORUN ATI MILIONU LONA OGORUN
Eleyii ni Gbogbo Owo ti Ijoba n sereti lati na fun isuna.
Apapo Inawo
Atigbadegba je:
Bilionu marundinlaadorin o le milionu lona
metalelaadota naira
Apapo Inawo lori Ise Akanse je:
Bilionu merindinlogoji o le milionu lona
egbeta naira
Atunyewo Eto Isuna Awa Arawa Ipinle Kogi
Personnel Cost
OverheadCost
N38.2bn N25.46bn
N1.87bn
Isuna ti a fowosiPersonnel Cost - N40.97bnOverhead Cost - N36.04bn
Interest Payments
(Public Debts)
10
Nibo ni Owo naa nlo?
Atupale Inawo
Atigbadegba
Inawo Lori
Awon Osise:
BILIONU LONA MEJIDINLOGOJI O LE MILIONU LONA
IGBA NAIRA
Inawo Ele Lori Isuna:
BILIONU MARUNDINLOGBON O LE MILIONU LONA MERINDINLAADOTA
NAIRA SISAN AWON ELE OWO
LORIN IGBESE:
BILIONU KAN O LE
MILIONU LONA
METADINLAADORUN
NAIRA
Atunyewo Eto Isuna Awa Arawa Ipinle Kogi 11
Aworan Awon Ibi Ti Owo Naa Nlo
INAWO LORI AWON OSISE
BILIONU LONA MEJIDINLOGOJI, MILIONU LONA IGBA O DIN META, EGBERUN LONA EGBETA O DIN MEJO ATI ORINLENIRINWO O DIN EYOKAN NAIRA (N38,197,592,479)
INAWO ELE LORI ISUNA:
BILIONU LONA METADINLOGBON, MILIONU LONA OODUNRUN O LE METADINLOGBON,
EGBERUN LONA EEDEGBERIN O LE METABINLAADOTA ATI OGBON NAIRA (N27,327,747,030)
ETO OGBIN:
BILIONU MERIN, MILIONU LONA ORINLENIRINWO O DIN EYOKAN ATI EGBERUN
LONA IRINWO O LE MERINDINLAADOTA NAIRA (N4,279,446,000)
BILIONU META, MILIONU LONA AADOJO EGBERUN LONA IRINWO O LE
MOKANLELAADORIN ATI EESANLELEEDEGBERIN NAIRA (N3,150,471,709)
ONA SISE:
BILIONU MARUN, MILIONU LONA ORINLELEGBERIN O LE MARUN ATI EGBERUN LONA EEDEGBETA NAIRA
(N5,885,500,000)
ETO ILERA:
BILIONU MEFA, MILIONU LONA ERINDINLAADOJO, EGBERUN LONA
OTALELOODUNRUN O DIN MERIN ATI EGBERUN O DIN MEJO NAIRA (N6,146,356,992)
IPESE OMI:
BILIONU KAN ATI MILIONU LONA OODUNRUN
O LE MEEDOGBON NAIRA (#1,325,000,000)
INA MANAMANA/IJOBA/ELENTIRIKI:
MILIONU LONA EGBETA O LE METADINLOGBON, EGBERUN MEJILA ATI EGBERIN NAIRA (N627,012,800)
ETO AABO
MILIONU LONA OGORUN O LE MEJILA ATI EGBERUN LONA MEJIDINLAADOTA
NAIRA (#112,048,000)
ODO ATI ERE IDARAYA
MILIONU LONA MERINLELEEDEGBETA ATI EGBERUN LONA ORINLENIRINWO
O DIN MEJO NAIRA (N504,472,000)
OOFIISI ATI ILE'GBE
BILIONU META, MILIONU LONA OJILELEEDEGBERIN O DIN MEWA ATI EGBERUN LONA OODUNRUN O LE
MERINDINLOGUN NAIRA (N3,730,316,000)
ETO IRINNA
BILIONU KAN, MILIONU LONA OTALELEEDEGBERUN O LE MARUN ATI
EGBERUN LONA ORINLENIRINWO NAIRA (N1,965,480,000)
ETO AYIKA
BILIONU MEJI, MILIONU LONA IGBA O LE MERIN ATI EGBERUN LONA IRINWO O LE MEJIDINLAADOTA NAIRA (N2,204,448,000)
ETO IROYIN, IBANISORO ATI IMO ERO:
BILIONU KAN, MILIONU LONA ERINLELAADOFA, EGBERUN LONA ORINLELOODUNRUN O LE
MERIN ATI EEDEGBETA NAIRA (N1,106,468,500)
OKOOWO ATI ISE
BILIONU KAN, MILIONU LONA OTALELOGORUN O DIN MERIN AT EGBERUN LONA ORINLELEGBETA O
LE MEJO NAIRA (N1,156,688,000)
IRINA JO IMOLUKA
MILIONU LONA OODUNRUN O LE MOKANDINLAADOTA, EGBERUN LONA OTALELOODUNRUN O LE MEFA ATI
IRINWO NAIRA (#349,366,400)
AWON AKANSE ISE IJOBA MIRAN
BILIONU MERIN, MILIONU LONA MERINLELAADOTA, EGBERUN LONA OTALELEEDEGBERIN O LE MEJI ATI
OKANLELOGUN NAIRA (N4,054,762,021)
ETO EKO:
Project/Donor Approved 2020Budget
Revised 2020Budget
Atunyewo Eto Isuna Awa Arawa Ipinle Kogi 12
Bawo ni Ijoba Yoo Se Ri Owo Iranlowo Gba?
OWO IRANLOWO PATAKI FUN IJOBA IPINLE
BILIONU KAN, MILIONU MEJO,
EGBERUN LONA EEDEGBETA O LE
METALA ATI OKOOLELOODUNRUN
O DIN KAN NAIRA (1,008,513,319)
OWO IRANLOWO LATI ODO IJOBA APAPO
FUN AYIKA ATI AGBARA OJO
----
OWO IRANLOWO FUN ILE-IWE ALAKOBERE TI
A MO SI UBEC
BILIONU KAN, MILIONU MEJILA,
EGBERUN LONA ORINLELEGBETA
O LE MEJI ATI ERINLELEEDEGBERIN
NAIRA (1,012,682,704)
EYO OWO IDA KAN FUN ITOJU APO OWO
JAAC
MILIONU LONA IRINWO NAIRA
(400,000,000)
ETO GBIGBA OKAN MILIONU LA
MILIONU LONA OODUNRUN
NAIRA (300,000,000)
EYO OWO IDA KAN NINU OWO IJOBA IBILE
FUN YIYE IWE OWO
WO
MILIONU LONA IRINWO O LE
AADOTA, EGBERUN LONA
OJILENIGBA O DIN EYOKAN ATI
IRINWO O LE MOKANLELOGBON
NAIRA (450,239,431)
AKOJOPO OWO LATI ODO AWON A JO MDA
MILIONU LONA OTALENIGBA
NAIRA (260,000,000)
EYO OWO IDA KAN NINU OWO IJOBA IBILE
FUN IDANILEKO FUN AWO N OSISE IJOBA
IBILE
MILIONU LONA IGBA, EGBERUN
LONA OTALELEGBERIN O DIN
MEJO ATI EEDEGBERIN NAIRA
(200,852,700)
AKOJOPO OWO LATI AWON IJOBA IBILE
MILIONU LONA AADOJO NAIRA
(150,000,000)
AKOJOPO OWO LATI ODO AWON OLODANNI
ATI AWON ILE ISE NLANLA
MILIONU LONA AADOTA
(50,000,000)
OWO IRANLOWO LATI ODO AJO YESSO ATI
A JO AGBANISISE FUN IDANILEKO NI ILE EKO
OLORE TI IJOBA ORILE EDE YII ATI ILE KOREA
MILIONU LONA OGOJI NAIRA
(40,000,000)
OWO TI A FUN NI LATI ODO IJOBA APAPO
FUN ARUN KORONA
BILIONU KAN NAIRA
(1,000,000,000)
AKOJOPO OWO LATI ODO OLODANNI ATI
AWON ILE ISE NLANLA FUN ARUN KORONA
BILIONU KAN NAIRA
(1,000,000,000)
IRANLOWO LATI ODO AWON AJO
IDAGBASOKE FUN ARUN KORONA
MILIONU LONA EEDEGBETA NAIRA
(500,000,000)
Atunyewo Eto Isuna Awa Arawa Ipinle Kogi
N3.23bn
N3bn
N0.23bn
13
Bawo ni ijoba yoo se ri owo iranlowo gba?
Akojopo owo iranlowo lati okeere je:
Bilionu meta ati milionu lona metalelogun naira
Ajo teekoto fun ipinle ati ajo SFTAS fun abajade to peye
Bilionu meta naira
Ajo YESSO fun idanileko pelu
ajosepo KOICA-LOKOJA
Milionu lona metalelogun
Atunyewo Eto Isuna Awa Arawa Ipinle Kogi
N5.4bnOlufunni
Approved
Budget
Atunyewo
Isuna
14
Bawo ni Ijoba Yoo Se Ri
Eyawo Gba ?
AKOJOPO EYAWO L'ABELE JE
Bilionu marun ati milionu lona irinwo naira
Eyawo lati odo awon ile
ifowopamo fun ipinle Kogi
Bilionu meji naira
(2,000,000,000)
Eyawo fun ilegbee
Bilionu kan naira
(1,000,000,000)
Ajo to nri si Apo ifowosi,
idagbasoke ohun
amayederun ati ajo
olufunni lowo
-------
Mimu ounje asaraloore ya
kiakia lorileede Nigeria
Milionu lona
irinwo naira
(400,000,000)
Eyawo lati odo ile
ifowopamo ijoba apapo ati
awon ile ifowopamo miran
fun arun korona
Bilionu meji naira
(2,000,000,000)
N2.91bn
Akanse Ise/Ile IseApproved
Budget
Atunyewo
Isuna
Atunyewo Eto Isuna Awa Arawa Ipinle Kogi 15
Bawo ni Ijoba Yoo Se
Ri Eyawo Gba ?
AKOJOPO EYAWO LATI OKEERE JE
Bilionu meji ati milionu
mokanle laadorun naira
Eyawo lati banki agbaye
lati fi seto ere oko ni ALAPE
Bilionu kan naira (1,000,000,000)
Iranlowo lati odo
banki
agbaye fun sise ojuna
igberiko ati itaja ohun
ogbin
Milionu lona
eedegbeta
(500,000,000)
Ajo NEW MAP
--------
Iranlowo lati odo banki
agbaye fun iseto ohun
ogbin ati igbe aye
Bilionu kan naira
(1,000,000,000)
Eto iranlowo banki agbaye
fun awon igberiko ati
nnkan amayederun
Milionu lona
oodunrun naira
(300,000,000)
Ajo YESSOMilionu lona aadofa
naira (110,000,000)
Atunyewo Eto Isuna Awa Arawa Ipinle Kogi
Government House 23,212,235,011 15,336,819,011
Deputy Governors Office 2,841,267,134 1,329,929,222
Office Of The Secretary To The State
Government 5,810,857,836 2,915,869,777
Kogi State House Of Assembly Service
Commission 6,595,634,518 8,535,873,681
Ministry Of Information And
Communication 1,508,605,793 3,501,993,014
Office Of The Head Of Civil Service 12,007,263,336 806,727,456
Office Of The State Auditor-general 1,164,236,829 714,569,604
Civil Service Commission 132,973,993 171,981,977
Local Government Service
Commission 387,125,968 4,742,075,832
Ministry Of Agriculture 11,455,059,911 10,362,489,026
Ministry Of Finance, Budget And
Economic Planning 17,925,492,167 892,437,567
Min. Of Commerce & Industry 1,959,926,025 442,810,964
Ministry Of Transport 1,216,135,581 6,204,082,634
Ministry Of Works And Housing 15,965,043,471 487,170,815
Min. Of Culture & Tourism 1,156,883,891 1,441,282,549
Ministry Of Water Resources 4,512,469,144 1,101,481,081
Bureau For Lands And Urban
Development 3,568,137,008 1,025,232,697
Ministry Of Rural Development 2,948,805,003 1,193,865,416
Kogi State Judicial Service
Commission 5,439,046,173 4,146,330,541
Ministry Of Justice 2,176,180,411 526,198,026
Ministry Of Youth & Sports 824,830,717 507,547,816
Ipin fun Eka
to ga/Ile Ise
Approved
Expenditure
Atunyewo Inawo
16
Ipinfuni Elekajeka
Olu ile ise ijoba
Bilionu meedogun, milionu lona
ojileloodunrun o din merin, egberun
lona okoolelegberin o dinkan ati naira
mokanla (15,336,819,011)
Ofiisi igbakeji gomina
Bilionu kan, milionu lona oodunrun o
le mokandinlogbon, egberun lona
eedegberun o le mokandinlogbon ati
okoolenigba o le meji naira
(1,329,929,222)
Ofiisi akowe fun ijoba
ipinle
Bilionu meji, milionu lona
eedegberun o le meedogun, egberun
lona otalelegberin o le mesan ati
orinleleedegberin o din meta naira
(2,915,869,777)
Ajo to nbojuto ile
igbimo asofin ipinle
Kogi
Bilionu mejo, milionu lona
ojileleedegbeta o din marun, egberun
lona orinlelegberin o din meje ati
orinlelegbeta o le eyokan naira
(8,535,873,681)
Ile ise iroyin/oro to nlo
ati ibanisoro
Bilionu meta, milionu lona
okanleleedegbeta, egberun lona
orinleleedegberun o le metala ati
naira merinla (3,501,993,014)
Ofiisi oga agba fun
awon osise ijoba
Milionu lona egberin o le mefa,
egberun lona okooleleedegberin o le
meje ati otalenirinwo o din merin
naira (806,727,456)
Ofiisi oluyeweowowo
agba fun ipinle
Milionu lona eedegberin o le merinl a,
egberun lona otaleleedegbeta o le
mesan ati erinlelegbeta naira
(714,569,604)
Ajo to n bojuto awon
osise ijoba
Milionu lona orinlelogorun o din
mesan, egberun lona
orinleleedegberun o lekan ati
orinleleedegberun o din meta naira
(171,981,977)
Ipinfuni Elekajeka
Atunyewo Eto Isuna Awa Arawa Ipinle Kogi 17
Ipin fun Eka
to ga/Ile Ise
Approved
Expenditure
Atunyewo Inawo
Ajo to nbojuto ijoba
ibile
Bilionu merin, milionu lona
ojileleedegberin o le meji, milionu
lona marundinlogorin ati
ojilelegberin o din mejo naira
(4,742,075,832)
Ile is eto ogbin Bilionu mewa, milionu lona
otaleloodunrun o le meji, egberun
lona orinlenirinwo o le mesan ati
naira merindinlogbon
(10,362,489,026)
Ile ise inawo, eto isuna
ati eto oro aje
Milionu lona orinlelegberin o le
mejila, egberun lona ojilenirinwo o
din meta ati otaleleedegbeta o le
meje naira (892,437,567)
Ile ise okoowo ati ise
Milionu lon a ijilenirinwo o le meji,
egberun lona egberin o le mewa ati
otaleleedegberun o le merin naira
(442,810,964)
Ile ise eto
irinna/igbokegbodo
Bilionu mefa, milionu lona
erinlenigba, egberun mejilelogorin ati
ojilelegbeta o din mefa naira
(6,204,082,634)
Ile ise ode ati ilegbee
Milionu lona orinlenirinwo o le meje,
egberun lona igba o din ogbon ati
okoolelegberin o din marun naira
(487,170,815)
Ile ise asa ati imoluka
Bilionu kan, milionu lona ojilenirinwo
o lekan, egberun lona orinlenigba o
lekan ati ojile leedegbeta o le mesan
naira (1,441,282,549)
Ile ise alumoni inu omi
Bilionu kan, milionu lona
okanlelogorun, egberun lona
orinlenirinwo o lekan ati naira
mokanlelogorin (1,101,481,081)
Ajo fun oro ile ati
idagbasoke ilu nlanla
Bilionu kan, milionu meedog bon,
egberun lona igba o le mejilelogbon
ati eedegberin o din meta naira
(1,025,232,697)
Ipinfuni Elekajeka
Atunyewo Eto Isuna Awa Arawa Ipinle Kogi 18
Ipin fun Eka
to ga/Ile Ise
Approved
Expenditure
Atunyewo Inawo
Ile ise idagbasoke
igberiko
Bilionu kan, milionu lona igba o din
meje, egberun lona otalelegberin o le
marun ati okoolenirinwo o din merin
naira (1,193,865,416)
Ajo to nbojuto eto
idajo ni ipinle Kogi
Bilionu merin, milionu lona
erindinlaadojo, egberun lona
ojileloodunrun o din mewa ati
ojileleedegbeta o lekan naira
(4,146,330,541)
Ile ise eto idajo
Milionu lona okooleleedegbeta o le
mefa, egberun lona igba o din meji ati
naira merindinlogbon (526,198,026)
Ile ise odo ati ere
idaraya
Milionu lona eedegbeta o le meje,
egberun lona ojileleedegbeta o le
meje ati okoolelegberin o din merin
naira (507,547,816)
Ile ise to nei si oro
awon obirin ati
idagbasoke ohun
amayederun
Bilionu metadinlogun, milionu lona
okooleleedegbeta, egberun lona
eedegbeta o din mefa ati eedegberin
o din merin naira (17,520,494,696)
Ile ise eto eko, imo
ijinle ati imo ero
Bilionu meedogun, milionu
merinlelaadota, egberun lona
otalenigba o din m erin ati
orinlelegberin o le metala naira
(15,054,256,893)
Ile ise eto ilera
Bilionu kan, milionu lona
okoolelegberin o le meta, egberun
lona orinleleedegbeta o le mefa ati
okanlenigba naira (1,823,586,201)
Ile ise eto ayika Milionu lona mokandinlaadorun ,
egberun lona okooleleedegberun o
din meta ati orinleleedegberun o
lekan naira (89,917,981)
Ile ise ijoba ibile ati oro
oye
Bilionu kan, milionu lona ojilenigba o
le mejo, egberun metadinlaadorin ati
otalenirinwo o din mefa naira
(1,248,067,454)
AWON ISE AKANSE TI ISUNA EGBAA ODUN O LE OKOO/OGUN FOWOSI
Atunyewo Eto Isuna Awa Arawa Ipinle Kogi 19
Akanse Ise IbiRevised
ExpenditureAjo/Ile Ise Ijoba Ibile
Atunyewo
Iye Owo
Idasile ibudo
sise aayan ire
oko
ile ise eto
ogbin
Alape
Kabba Bunu
Bilionu kan ati
milionu lona
eedegbeta naira
(1,500,000)
Kiko ile iwosan
idarienisi ni
Okene
Ile ise eto
ilera
Okene
Okene
Bilionu meji ati
milionu lona
aadotaleleedegbeta
naira (2,550,000,000)
Kikapa agbara
ojo
Ile ise eto
ayika
Jakejado
ipinle
Jakejado ipinle
Milionu lona
eedegbeta naira
(500,000,000)
Rira oko fun
fun awon ile
ise ijoba ati
awon eka
Ofiisi oga
agba ni ile ise
ijoba
Olu ile ise
ijoba
Lokoja
Bilionu kan naira
(1,000,000,000)
Ipese omi fun
Lokoja nla apa
keji
Ile ise eto
ohun alumoni
inu omi
Olu ile ise
ijoba
Lokoja
Bilionu meji naira
(2,000,000,000)
Pipari
ibudo
iyeraeniwo ati
aworan ilera
igbalode pelu
awon irin ise
Ile ise eto
ilera
Olu ile ise
ijoba
Lokoja
Bilionu meji naira
(2,000,000,000)
Kiko ibi abo
fun isele ojiji ni
gbogbo awon
opopona
Pataki laarin
ipinle
Ile ise eto ise
ati ilegbee
Jakejado
ipinle
Jakejado ipinle
Bilionu kan ati
milionu lona
otalelegbeta o din
mewa naira
(1,650,000,000)
Isopo ijoba lori
ise akanseIle ijoba
Jakejado
ipinleJakejado ipinle
Bilionu kan ati
milionu lona
eedegbeta naira
(1,500,000,000)
Ajo to nboju
atunse awon
oju ona ni
ipinle Kogi
Ajo to n
bojuto oju
ona
Jakejado
ipinleJakejado ipinle
Milionu lona ogorun
naira (100,000,000)
Atunyewo Eto Isuna Awa Arawa Ipinle Kogi 20
Akanse Ise IbiRevised
ExpenditureAjo/Ile Ise Ijoba Ibile
Atunyewo
Iye Owo
Atunko awon
iyara ikekoo ni
awon ile iwe
alakobere ati
awon ile iwe
giga
Ile ise eto eko,
sayensi ati
imo ero
Jakejado
ipinle
Jakejado ipinle
Milionu lona aadojo
naira (150,000,000)
Atunko ati fife
ayika ikekoo
ile iwe
mejilelogoji.
Meji fun ijoba
ibile kookan
(ogun ati
awose GYB)
Ile ise eto eko,
sayensi ati
imo ero
Jakejado
ipinle
Jakejado ipinle
Milionu lona ogorun
naira (100,000,000)
Ise akanse
elekunjekun
Ile igbimo
asofin ipinle
Kogi
Jakejado
ipinle
Jakejado ipinle
Milionu lona
eedegbeta naira
(500,000,000)
Owo Pataki
fun ajo eleto
idibo ipinle lati
seto idibo
ijoba ibile
Ajo eleto idibo
ipinle
Jakejado
ipinle
Jakejado ipinle
Milionu lona ogorun
naira (100,000,000)
Ituyayajade
akanse ise
ogbin ni ipinle
Kogi
Ile ise eto
ogbin
Jakejado
ipinle
Jakejado ipinle
Milionu lona ogorun
naira (100,000,000)
Awon ona ti a
sa yan ni ekun
aarin
gbungbun
asojusofin
Ile ise eto ise
ati ilegbee
Ekun aarin
gbungbun
asojusofin
Okene, Okehi,
Adavi, Ajaokuta
ati
Ogori/Magongo
Bilionu kan naira
Igbesoke ile
ise amunawa
fun awon ijoba
ibile ati
igberiko
Ile ise eto
idagbasoke
igberiko
Ekun ila
oorun
asojusofin
Idah, Ankpa,
Ibaji, Ofu,
Olamaboro,
Omala, Dekina,
Igalamela ati
Bassa
Milionu lona
merinlelogorun ati
egberun lona egberin
naira (104,800,000)