Upload
others
View
0
Download
0
Embed Size (px)
Citation preview
EBOLA • Ebola ńbẹ ó sì máa ń pani? • Ebola ń ràn ní àwọn àgbègbè báyì • Láti ṣe àìsàn, o gbọ́dọ̀ ní ÌFÀRAKANRA
TÀÀRÀ pẹ̀lú aláìsàn tàbí omi ara won
• Àwọn òògùn asòdìsì-kòkòrò kìí pa Ebola
• Yára gba ìtọjú kíákíá ní ibi àbojútó Ebola. Èyí fààyè gba ìmúláradá
Ìfàrakanra pẹ̀lú òkú lè fa àìsàn. SỌ́RA (Sìnkú pẹ̀lú ìsọ́ra. Yẹra)
• MÁṢE fọ̀, fọwọ́kàn tàbí fi ẹnu ko ara òkú
• MÁṢE fọ ọwọ́ nínú garawa tàbí korobá kan náà pẹ̀lú àwọn ẹlòmíràn tó ti fọwọ́kan òkú náà
KÍNI EBOLA ÀTI BÁWO NI O SE Ń RÀN?
SYMPTOMS Lè bẹ̀rẹ̀ láti ọjọ́ kejì sí ọjọ́ kọkànlélógún (2-21) lẹ́yìn tí ènìyàn bá ṣe alábàápàdé ẹnití ó ti ní àìsàn náà tàbí pẹ̀lú ara rẹ̀
ÀWỌN ÀMÌ ÀKỌ"KỌ" ÀÌSÀN NÁÀ ÀWỌN ÀMÌ ÀÌSÀN NÁÀ MÌÍRÀN NÍGBÀTÍ Ó BÁ PẸ"
IBÀ INÚ RÍRU ORÍ FÍFỌ́ ÌRẸRA ÈÉBÌ ÌGBẸ́ GBUURU IKỌ́ Ẹ̀JẸ̀ SÍSUN
• LÈ KÓ EBOLA LÁTI ARA ẸNITÍ N ṢÀÌSÀN TÀBÍ ẸNITÍ Ó TI KÚ
• MÁ A FỌ ỌWỌ́ RẸ NÍGBÀ GBOGBO - Lo ỌṢẸ (Bí o kò bá lè fọ̀ ọ́, lo ìpara tó ní ọtí-líle nínú)
• Máṣe fọwọ́kan àwọn ẹnití ó ní àrùn náà tàbí omi ara wọn Ẹ̀JẸ̀, ÈÉBÌ, ÌGBẸ́ TÀBÍ ÌGBẸ́ GBUURU, ÌTỌ̀
EBOLA wà lára ẹranko àti àdán pẹ̀lú • Jẹ ẹran tí a sè dáradára nìkan • Yẹra fún àwọn ẹran igbó tí ó sàìsàn tàbí tikú • Yẹra fún àwọn àdán àti ẹran àdán
Bí o bá sàìsàn tàbí fọwọ́kan aláìsàn tàbí omi ara wọn:
• Pe ibi àyẹ̀wò ìtọjú re
• Se ìgbọràn sí ìmọràn. Alè rán ọ lọsí Ilé-ìwosàn àkanse
• Máse jẹ́kí ẹnikẹ́ni fọwọ́kàn ọ́
• Sọ́ra dáradára fún Èébì tàbí ìgbẹ́-gbuuru re
ÌDÈNÀ ÀRÙN
A ṣe àgbékalẹ̀ àlàyé yìí fún èrèdí ẹ̀kọ́ nìkan, ó sì jẹ́ òtítọ́ ní àsìkò tí a ṣe àgbéjáde rẹ̀. Kìí ṣe pàṣípààrọ̀ fún ìmọ̀ràn láti ọwọ́ akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ òṣìṣẹ́ ìlera rárá. Bí o.bá ní ìbéèrè tàbí àníyàn Kankan nípa kókó-ọ̀rọ̀ yòówù tí a ṣe àlàyé rẹ̀, jọ̀wọ́ kàn sí akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ òṣìṣẹ́ ìlera rẹ.kiafya.
© 2014 AEA International Holdings Pte. Ltd. All rights reserved. Unauthorised copy or distribution prohibited. 17 November 2014 YORUBA For more information: www.internationalsos.com/ebola
Lè ní ẹ̀jẹ̀ nínú
(láti imú, ẹnu, awọ-ara)
Rírí àti gbígba ìtọjú kíákíá ní ibi àbojútó Ebola fún ọ ní ànfààní ìpadabọ̀sípò
Lè ní ẹ̀jẹ̀ nínú Lè ní ẹ̀jẹ̀ nínú
OHUN TÍ O LÈ ṢE bí o bá n ṣàìsàn
Àwọn ẹnití ó wà pẹ̀lú aláìsàn náà ni ó wà lábẹ́ ewu tó pọ̀ jù:
• Àwọn ẹbí • Àwọn òṣìṣẹ́ ìlera