2
ÌF́ PLPYIO DI TÚTÙ Ati nitori ẹṣ ̀ yio di pip, ifẹ ọplpyio di tutù. ugbn niti o ba foritì i titi de opin, on na li a o gbalà (Matteu 24:12-13). A o si wasu IHINRERE IJOBA yi ni gbogbo aiye lati e ri fun gbogbo oril-ède; nigbana li opin yio si de (Matteu 24:14; Marku 13:10). ÌRÍRA ISDAHORO NI JERUSALMU Nigbati nyin ba si ri ti a fi ogun yi Jerusalmu ká, m̀ nigbana pe, isdahoro r̀ kù si dd ̀ (Luku 21:20). Nitorina nigbati nyin ba ri irira isdahoro, ti a ti nu wolĩ Danieli s, ti o ba duro ni ibi mim, ́ (niti o ba kà a, ki òye ki o yé e:), nigbana ni ki awn ti mbni Judea ki o sálsi ori òke: ati awn ti mblarin r̀ ki nwn jade kuro; ki awn ti o si mbni igberiko ki o máe ẁ inu r̀ l. Ki niti mblori ile ki o máe skallsinu ile, bn ̃ i ki o má si e ẁ inu r, ̀ lati mu ohunkohun jade ninu ile r: ̀ Ati ki niti mbli oko ki o mae pada shin wá lati mu aṣọ r̀ (Matteu 24:15-18; Marku 13:14-16; Luku 17:31; 21:21). ugbn egbé ni fun awn ti o lóyun, ati fun awn ti o nfi mu fun mmu li jwnni! Ki si ma gbadura, ki sisá nyin ki o máe b́ si igba otutù, tabi jisimi (Matteu 24:19-20; Marku 13:17-18; Luku 21:23). Nwn o si ti oju idà ubu, a o si dì wn ni igbekun lsi oril-ède gbogbo: Jerusalemu yio si di itmlli sawn Keferi, titi akoko awn Keferi yio fi kún (Luku 21:24). ÀKOKO WAHALA FUN JAKBU (Jer 30:6-7) Nitori jwnni, yio jẹ ọjipnju irú eyi ti kò si lati igba jìwa ti lrun da, titi fi di akokò yi, irú r̀ ki yio si si, ati ibinu si awn enia wnyi. Bi ko si e bi Oluwa ti ke jwnni kuru, kò si da ti iba le là: ugbn nitoriti awn ayanfti o ti yàn, li a o fi ké jwnni kuru (Matteu 24:21-22; Marku 13:19-20; Luku 21:23). Nitori jsan li jwnni, ki a le mu ohun gbogbo ti a ti kwe r̀ ṣẹ (Luku 21:22). EKE KRISTI ATI EKE WOLI Nigbana bi nikan ba wi fun nyin pe, wo o, Kristi mbnihinyi; tabi, wo o, o mblh ́ un; e gbà a gb: ́ Nitori awn eke Kristi, ati eke woli yio dide, nwn o si fi àmi ati ohun iyanu nla hàn, tob̃ bi o le e e nwn o tàn awn ayanfpãpã. ugbn kiyesara: wo o, mo sohun gbogbo fun nyin tl(Matteu 24:23-24; Marku 13:21-23). Nitorina bi nwn ba wi fun nyin pe, Wo o, o wà li aginjù; má lsib, ̀ tabi wo o, o wà ni iywu; e gbàgb. ́ Nitori ggbi manamana ti iklati ila-õrun, ti isi mlde ìw-õrun; bn ̃ i wiwa m-enia yio ri plu (Matteu 24:26-27; Luku 17:23-24). ÀMI LI R ̀ UN Lojukanna lhin ipnju jwnni àmi yio si wà: õrùn yio õkun, oupá kì yio si fi imlr̀ hàn, awn irawyio ti oju run já sil, agbara oju run li a o si mì titi (Matteu 24:29; Marku 13:24-25; Luku 21:25). Àti lori ilaiye idamu fun awn oril-ede nitori ipaiya ti ariwo; Aiya awn enia yio ma já fun ibru, ati fun ireti nkan wnni ti mb̀ sori aiye (Luku 21:25-26). Nigbana li ÀMI M-ENIA yio si fi ara hàn li run; nigbana ni gbogbo Jesu Kristi Olúwa n'padà b̀ s'oril̀ láì pláì jìnà. Èyí ni ìlérí ti Olúwa e nígbàti ó ì wa l'áiyé yi ni gbw ́ a dún sh ́ ìn (Johanu 14:1-3). A le ma ro wi pe bawo ni o e daju pe yio si pada b. jw ̀ ka awn astlohun isl ̀ ̀ ti Jesu Olúwa spe yio ski ohun to pada. Aywo finifini s'inu ìwé míḿ ati ohun ti o nslninu aiye lw ́ l ́ w ́ ́ bayi fihan wipe Jesu Oluwa yi o pada bo ni aiye t'awa yi. ÌPARUN TEMPILI Jesu si jade l, o ti tmpili kuro: awn m-hin r̀ si t̀ wá lati fi kiḱ tmpili hàn a. o si wipe: Olukni, wò irú okuta ati irú ile ti o wà nihinyi! Jesu si wi fun wn pe, nyin kò ri gbogbo nkan wnyi? lõtni mo wi fun nyin, Kì yio si okuta kan nihinyi ti a o fi sillori ekeji, ti a kì yio wó lul(Matteu 24:1- 2; Marku 13:1-2; Luku 21:5-6). Eleyi wá sí ìmúní adrin dún lh ́ ìn ikú Jesu Kristi. ÀMÍ ÌPADÀWÁ Bi o si ti joko lori òke Olifi ti o kju si tmpili, awn mọ-ẹhin r̀ Peteru ati Jakbu, ati Johanu ati Anderu, bi i lre nikk ̀ wipe, olukni Sfun wa, nigbawo ni nkan wnyi yio ṣẹ? kini yio si e àmi wíwa r, ati ti opin aiye nigbati gbogbo nkan wnyi yio ṣẹ? (Matteu 24:3; Marku 13:3-4; Luku 21:7). LT ̀ ÀN YIO DÌDE Jesu si dahùn, o si wi fun wn pe, kiyesara, ki nikni ki o máe tàn nyin j. Nitori plpyio wá li orukmi, wipe, Emi ni Kristi; akokò igbana si kù si dẹd ̀ : nwn ó si tàn p ̀ ọlọpọ jẹ, ẹ e t̀ wn lhin (Matteu 24:4-5; Marku 13:5-6; Luku 21:8). OGUN ATI IDAGÌRI OGUN Nigbati nyin ba si ngburó ogun ati idagìri ogun; ki nyin ki o máe jaiya: nitori irú nkan wnyi kò le e ki o ma ṣẹ; ugbn opin na kì ie isisiyi (Matteu 24:6; Marku 13:7; Luku 21:9). 1 2 3 OGUN Y ̀ Á | IṢẸLNLA | ÌYAN | ÀRÙN Nigbana li o wi fun wn pe, Orilẹ-ède yio dide si oril-ède, ati ilẹ-ọba si ilẹ-ọba: Islnla yio si wà kakiri, ati ìyan ati ajakalarùn; ohun r ̀ u, ati àmi nla yio si ti run wá (Matteu 24:7; Marku 13:8; Luku 21:10-11). Gbogbo nkan wnyi ni ipilẹṣẹ ipnju (Matteu 24:8; Marku 13:8). INUNIBINI SI AWON KRISTIANI ugbn mã kiyesara nyin: nwn o naẃ mu nyin, nwn o si e inunibini si nyin, nitori nwn ó si fi nyin le awn igbimlw; a o si lù nyin ninu sinagogu: nwn o fi nyin sinu tubu, nwn o fi nyin funni lati jni ìya, nwn o si pa nyin, nwn o mu nyin lsdawn ba ati awn ijoye nitori orukmi. Yio si pada di rí fun nyin (Matteu 24:9; Marku 13:9; Luku 21:12-13). ugbn nigbati nwn ba nfà nyin, l, ti nwn ba si nfi nyin le wn lw, pinnu r̀ li kàn nyin pe kì yio ronu aju, bi o ti dahun, ugbn ohun ti a ba fifun nyin ni wakati na, on ni ki nyin ki o wi: nitori kì ie nyin ni nwi, bikoe mí Mim. ́ Nitoriti emi ó fun nyin li nu ati gbn ́ , ti gbogbo awn tá nyin kì yio le sr-òdi si, ti nwn kì yio si le kò loju (Marku 13:11; Luku 21:14-15). BÍ YIO FI ARA WN HÀN Arakunrin yio si fi arakunrin fun pipa, ati baba yio fi mr̀ hàn; awn myio si dide si obi wn, nwn o si mu ki a pa wn. A o si korira nyin ldgbogbo enia nitori orukmi. ugbn irun ori nyin kan kì o egbé. Ninu sũru nyin li nyin o jère kàn nyin (Matteu 24:9-10; Marku 13:12-13; Luku 21:16- 19). 4 5 6 7 8 11 12 13 9 14 10 15 16

Nigerian dialect-v4 5 - edge.sin1.swiftserve.comedge.sin1.swiftserve.com/angeltv/angeltvlfd/downloads/GOTK...li ojijì, ki o máṣe ba nyin li oju orun (Marku 13:34-36). Ṣugbọn

Embed Size (px)

Citation preview

Page 1: Nigerian dialect-v4 5 - edge.sin1.swiftserve.comedge.sin1.swiftserve.com/angeltv/angeltvlfd/downloads/GOTK...li ojijì, ki o máṣe ba nyin li oju orun (Marku 13:34-36). Ṣugbọn

ÌFẸ ỌPỌLỌPỌ YIO DI TÚTÙAti nitori ẹṣ ẹ yio di pipọ, ifẹ ọpọlọpọ

yio di tutù. Ṣugbọn ẹniti o ba foritì i titi de opin, on na li a o gbalà (Matteu 24:12-13).

A o si wasu IHINRERE IJOBA yi ni gbogbo aiye lati ṣe ẹri fun gbogbo

orilẹ-ède; nigbana li opin yio si de (Matteu

24:14; Marku 13:10).

ÌRÍRA ISỌDAHORO NI JERUSALẸMU

Nigbati ẹnyin ba si ri ti a fi ogun yi Jerusalẹmu ká, ẹ mọ nigbana pe, isọdahoro rẹ kù si dẹd ẹ (Luku 21:20). Nitorina nigbati ẹnyin ba ri irira isọdahoro, ti a ti ẹnu wolĩ Danieli sọ, ti o ba duro ni ibi mimọ, (ẹniti o ba kà a, ki òye ki o yé e:), nigbana ni ki awọn ti mbẹ ni Judea ki o sálọ si ori òke: ati awọn ti mbẹ larin rẹ ki nwọn jade kuro; ki awọn ti o si mbẹ ni igberiko ki o máṣe wọ inu rẹ lọ. Ki ẹniti mbẹ lori ile ki o máṣe sọkalẹ lọ sinu ile, bẹn i ki o má si ṣe wọ inu rẹ, lati mu ohunkohun jade ninu ile rẹ: Ati ki ẹniti mbẹ li oko ki o maṣe pada sẹhin wá lati mu aṣọ rẹ (Matteu 24:15-18;

Marku 13:14-16; Luku 17:31; 21:21). Ṣugbọn egbé ni fun awọn ti o lóyun, ati fun awọn ti o nfi ọmu fun ọmọ mu li ọjọ wọnni! Ki ẹ si ma gbadura, ki sisá nyin ki o máṣe bọ si igba otutù, tabi ọjọ isimi (Matteu 24:19-20; Marku

13:17-18; Luku 21:23). Nwọn o si ti oju idà ṣubu, a o si dì wọn ni igbekun lọ si orilẹ-ède gbogbo: Jerusalemu yio si di itẹmọlẹ li ẹsẹ awọn Keferi, titi akoko awọn Keferi yio fi kún (Luku 21:24).

ÀKOKO WAHALA FUN JAKỌBU (Jer

30:6-7)Nitori ọjọ wọnni, yio jẹ ọjọ ipọnju irú eyi ti kò si lati igba ọjọ ìwa ti Ọlọrun da, titi fi di akokò yi, irú rẹ ki yio si si, ati ibinu si awọn enia

wọnyi. Bi ko si ṣe bi Oluwa ti ke ọjọ wọnni kuru, kò si ẹda ti iba le là: ṣugbọn nitoriti awọn ayanfẹ ti o ti yàn, li a o fi ké ọjọ wọnni kuru (Matteu 24:21-22; Marku 13:19-20; Luku

21:23). Nitori ọjọ ẹsan li ọjọ wọnni, ki a le mu ohun gbogbo ti a ti kọwe rẹ ṣẹ (Luku 21:22).

EKE KRISTI ATI EKE WOLINigbana bi ẹnikan ba wi fun nyin pe,

wo o, Kristi mbẹ nihinyi; tabi, wo o, o mbẹ lọh un; ẹ máṣe gbà a gbọ: Nitori awọn eke Kristi, ati eke woli yio dide, nwọn o si fi àmi ati ohun iyanu nla hàn, tobẹ bi o le ṣe ṣe nwọn o tàn awọn ayanfẹ pãpã. Ṣugbọn ẹ kiyesara: wo o, mo sọ ohun gbogbo fun nyin tẹlẹ (Matteu 24:23-24; Marku 13:21-23). Nitorina bi nwọn ba wi fun nyin pe, Wo o, o wà li aginjù; ẹ má lọ sibẹ, tabi wo o, o wà ni iyẹwu; ẹ máṣe gbàgbọ. Nitori gẹgẹ bi manamana ti ikọ lati ila-õrun, ti isi mọlẹ de ìwọ-õrun; bẹn i wiwa Ọmọ-enia yio ri pẹlu

(Matteu 24:26-27; Luku 17:23-24).

ÀMI LI ỌR UNLojukanna lẹhin ipọnju ọjọ wọnni

àmi yio si wà: õrùn yio ṣõkun, oṣupá kì yio si fi imọlẹ rẹ hàn, awọn irawọ yio ti oju ọrun já silẹ, agbara oju ọrun li a o si mì titi (Matteu

24:29; Marku 13:24-25; Luku 21:25). Àti lori ilẹ aiye idamu fun awọn orilẹ-ede nitori ipaiya ti ariwo; Aiya awọn enia yio ma já fun ibẹru, ati fun ireti nkan wọnni ti mbọ sori aiye (Luku 21:25-26).

Nigbana li ÀMI ỌMỌ-ENIA yio si fi ara hàn li ọrun; nigbana ni gbogbo

Jesu Kristi Olúwa n'padà bọ s'orilẹ láì pẹ láì jìnà. Èyí ni ìlérí ti Olúwa ṣe nígbàti ó ṣì wa l'áiyé yi ni ẹgbẹw a ọdún sẹh ìn (Johanu 14:1-3). A le ma ro wi pe bawo ni o ṣe daju pe yio si pada bọ. Ẹ jọw ọ ẹ ka awọn asọtẹlẹ ohun isẹl ẹ ti Jesu Olúwa sọ pe yio sẹ ki ohun to pada. Ayẹwo finifini s'inu ìwé mímọ ati ohun ti o nsẹlẹ ninu aiye lọw ọl ọw ọ bayi fihan wipe Jesu Oluwa yi o pada bo ni aiye t'awa yi.

ÌPARUN TEMPILIJesu si jade lọ, o ti tẹmpili kuro: awọn

ọmọ-ẹhin rẹ si tọ ọ wá lati fi kikọ tẹmpili hàn a. o si wipe: Olukọni, wò irú okuta ati irú ile ti o wà nihinyi! Jesu si wi fun wọn pe, Ẹnyin kò ri gbogbo nkan wọnyi? lõtọ ni mo wi fun nyin, Kì yio si okuta kan nihinyi ti a o fi silẹ lori ekeji, ti a kì yio wó lulẹ (Matteu 24:1-

2; Marku 13:1-2; Luku 21:5-6). Eleyi wá sí ìmúṣẹ ní adọrin ọdún lẹh ìn ikú Jesu Kristi.

ÀMÍ ÌPADÀWÁBi o si ti joko lori òke Olifi ti o kọju si

tẹmpili, awọn ọmọ-ẹhin rẹ Peteru ati Jakọbu, ati Johanu ati Anderu, bi i lẽre nikọk ọ wipe, olukọni Sọ fun wa, nigbawo ni nkan wọnyi yio ṣẹ? kini yio si ṣe àmi wíwa rẹ, ati ti opin aiye nigbati gbogbo nkan wọnyi yio ṣẹ? (Matteu 24:3; Marku 13:3-4; Luku 21:7).

ẸLẸT ÀN YIO DÌDEJesu si dahùn, o si wi fun wọn pe, Ẹ

kiyesara, ki ẹnikẹni ki o máṣe tàn nyin jẹ. Nitori ọpọlọpọ yio wá li orukọ mi, wipe, Emi ni Kristi; akokò igbana si kù si dẹd ẹ: nwọn ó si tàn ọp ọlọpọ jẹ, ẹ máṣe tọ wọn lẹhin (Matteu

24:4-5; Marku 13:5-6; Luku 21:8).

OGUN ATI IDAGÌRI OGUNNigbati ẹnyin ba si ngburó ogun ati

idagìri ogun; ki ẹnyin ki o máṣe jaiya: nitori irú nkan wọnyi kò le ṣe ki o ma ṣẹ; ṣugbọn opin na kì iṣe isisiyi (Matteu 24:6; Marku 13:7;

Luku 21:9).

1

2

3

OGUN ẸY Á | IṢẸLẸ NLA | ÌYAN | ÀRÙNNigbana li o wi fun wọn pe, Orilẹ-ède

yio dide si orilẹ-ède, ati ilẹ-ọba si ilẹ-ọba: Isẹlẹ nla yio si wà kakiri, ati ìyan ati ajakalẹ arùn; ohun ẹr u, ati àmi nla yio si ti ọrun wá (Matteu 24:7; Marku 13:8; Luku 21:10-11).

Gbogbo nkan wọnyi ni ipilẹṣẹ ipọnju

(Matteu 24:8; Marku 13:8).

INUNIBINI SI AWON KRISTIANIṢugbọn ẹ mã kiyesara nyin: nwọn o

nawọ mu nyin, nwọn o si ṣe inunibini si nyin, nitori nwọn ó si fi nyin le awọn igbimọ lọwọ; a o si lù nyin ninu sinagogu: nwọn o fi nyin sinu tubu, nwọn o fi nyin funni lati jẹ ni ìya, nwọn o si pa nyin, nwọn o mu nyin lọ sọdọ awọn ọba ati awọn ijoye nitori orukọ mi. Yio si pada di ẹrí fun nyin

(Matteu 24:9; Marku 13:9; Luku 21:12-13).

Ṣugbọn nigbati nwọn ba nfà nyin, lọ, ti nwọn ba si nfi nyin le wọn lọwọ, ẹ

pinnu rẹ li ọkàn nyin pe ẹ kì yio ronu ṣaju, bi ẹ o ti dahun, ṣugbọn ohun ti a ba fifun nyin ni wakati na, on ni ki ẹnyin ki o wi: nitori kì iṣe ẹnyin ni nwi, bikoṣe Ẹmí Mimọ. Nitoriti emi ó fun nyin li ẹnu ati ọgbọn , ti gbogbo awọn ọtá nyin kì yio le sọrọ-òdi si, ti nwọn kì yio si le kò loju (Marku 13:11; Luku 21:14-15).

ẸBÍ YIO FI ARA WỌN HÀNArakunrin yio si fi arakunrin fun pipa,

ati baba yio fi ọmọ rẹ hàn; awọn ọmọ yio si dide si obi wọn, nwọn o si mu ki a pa wọn. A o si korira nyin lọdọ gbogbo enia nitori orukọ mi. Ṣugbọn irun ori nyin kan kì o ṣegbé. Ninu sũru nyin li ẹnyin o jère ọkàn nyin (Matteu 24:9-10; Marku 13:12-13; Luku 21:16-

19).

4

5

67

8

The Gospel of the Kingdom of God_ _INSIDE07MAR012jesus ministries

11

12

139

14

10

15

16

Page 2: Nigerian dialect-v4 5 - edge.sin1.swiftserve.comedge.sin1.swiftserve.com/angeltv/angeltvlfd/downloads/GOTK...li ojijì, ki o máṣe ba nyin li oju orun (Marku 13:34-36). Ṣugbọn

ẹya aiye yio kãnu, nwọn o si ri Ọmọ-enia ti yio ma ti oju ọrun bọ ti on ti agbara ati ogo nla. Yio si rán awọn angẹli rẹ ti awọn ti ohùn ipè nla, nwọn o si kó gbogbo awọn ayanfẹ rẹ lati ori igun mẹrẹrin aiye jọ, lati ikangun aiye titi de ikangun ọrun (Matteu 24:30-31;

Marku 13:26-27; Luku 21:27).

Ṣugbọn nigbati nkan wọnyi ba bẹrẹ si iṣẹ, njẹ ki ẹ wò òke, ki ẹ si gbé ori nyin

soke; nitori idande nyin kù si dẹdẹ (Luku

21:28).

O si pa owe kan fun wọn pe; Ẹ kiyesi igi ọpọtọ, ati si gbogbo igi; Nigbati

nwọn ba rúwe, ti ẹká rẹ ba yọ titun ẹnyin ri i, ẹ si mọ fun ara nyin pe, igba ẹr un kù fẹfẹ. Gẹgẹ bẹ na li ẹnyin, nigbati ẹnyin ba ri nkan wọnyi ti nṣẹ, ki ẹnyin ki o mọ pe, ijọba Ọlọrun kù si dẹdẹ (Mattheu 24:32-33; Marku

13:28-29; Luku 21:29-31). Ṣugbọn niti ọjọ ati wakati na, kò si ẹnikan ti o mọ ọ, kò si, ki tilẹ iṣe awọn angẹli ọrun, tabi Ọmọ, bikoṣe Baba mi nikanṣoṣo (Matteu 24:36; Marku 13:32).

Bi o si ti ri li ỌJỌ NOA, bẹn i wíwa Ọmọ-enia yio si ri. Nitori bi ọjọ

wọnni ti wà ṣiwaju kikún omi, ti nwọn njẹ, ti nwọn nmu, ti nwọn ngbé iyawo, ti a si nfa iyawo funni, titi o fi di ọjọ ti Noa fi bọ sinu ọkọ, Nwọn kò si mọ titi omi fi de, ti o si run gbogbo wọn; gẹgẹ bẹn i wíwa Ọmọ-enia yio ri pẹlu (Matteu 24:37-39; Luku 17:26-27).

Gẹgẹ bi o si ti ri li ỌJỌ LOTI; nwọn njẹ, nwọn nmu, nwọn nrà, nwọn

ntà, nwọn ngbìn, nwọn nkọle; Ṣugbọn li ọjọ na ti Loti jade kuro ni Sodomu, ojo ina ati sulfuru rọ lati ọrun wá, o si run gbogbo wọn. Gẹgẹ bẹn i yio ri li ọjọ na ti Ọmọ-enia yio farahàn (Luku 17:28-30).

Ẹ ranti aya Loti. Ẹnikẹni ti o ba nwá ati gbà ẹmi rẹ là yio sọ ọ nù; ẹnikẹni

ti o ba si sọ ọ nù yio gbà a là (Luku 17:32-33).

Mo wi fun nyin, li oru ọjọ na, enia meji yio wà lori akete kan; a o mu ọkan, a o si fi ekeji silẹ. Enia meji yio si ma lọ ọlọ

pọ; a o mu ọkan, a o si fi ekeji silẹ. Enia meji yio wà li oko; a o mu ọkan, a o si fi ekeji silẹ (Matteu

24:40-41; Luku 17:34-36). Nwọn si da a lohùn, nwọn bi i pe, Nibo, Oluwa? O si wi fun wọn pe, Nibiti okú ba gbé wà, nibẹ pẹlu ni idì ikojọ pọ si (Matteu 24:28; Luku 17:37).

Ẹ MA ṢỌNA Ẹ SI MA GBADURANitori Ọmọ-enia dabi ọkunrin kan ti o

lọ si àjo ti o jìna rére, ẹniti o fi ile rẹ silẹ, ti o si fi aṣẹ fun awọn ọmọ-ọdọ rẹ, ati iṣẹ olukuluku fun u, ti o si fi aṣẹ fun oluṣọna ki o mã ṣọna. Nitorina ẹ mã ṣọna: nitori ẹnyin ko mọ igba ti bãle ile mbọw á, bi li alẹ ni, tabi larin ọganjọ, tabi li akukọ, tabi li owurọ: Pe, nigbati o ba de li ojijì, ki o máṣe ba nyin li oju orun (Marku 13:34-36).

Ṣugbọn ki ẹnyin ki o mọ eyi pe, bãle ile iba mọ wakati na ti olè yio wá, iba ma

ṣọna, on kì ba ti jẹ ki a runlẹ ile rẹ. Nitorina ki ẹnyin ki o mura silẹ: nitori ni wakati ti ẹnyin kò rò tẹlẹ li Ọmọ-enia yio de (Matteu 24:43-44).

Ṣugbọn ẹ mã kiyesara nyin, ki ọkàn nyin ki o máṣe kún fun wọb ia, ati fun

ọti amupara, ati fun aniyan aiye yi, ti ọjọ na yio si fi de ba nyin lojijì. Ẹ mã ṣọra, ki ẹ si mã gbadura: nitori ẹnyin ko mọ igbati akokò na yio de. Nitori bi ikẹkun ni yio de ba gbogbo awọn ti ngbe ori gbogbo ilẹ aiye (Marku 13:33; Luku 21:34-35).

21 Ohun tí mo wí fun yín, mo wi fún gbogbo ènìà, Njẹ ki ẹ mã ṣọna, ki ẹ si

mã gbadura nigbagbogbo, ki ẹ ba le là gbogbo nkan wọnyi ti mbọ wá iṣẹ, ki ẹ si le duro niwaju Ọmọ-enia (Luku 21:36).

Lõtọ ni mo wi fun nyin, Iran yi kì yio rekọja, titi a o fi mu gbogbo nkan

wọnyi ṣẹ. Ọrun on aiye yio rekọja: ṣugbọn ọr ọ mi kì yio rekọja (Matteu 24:34-35; Marku

13:30-31; Luku 21:32-33).

The Gospel of the Kingdom of God_07MAR012_OUTSIDEjesus ministries

www.angeltv.org

Wo ANGEL TV

ÈDÈE YORUBA | AFRICA

17

18

20

19

23

22

24

25

26

27

Local Contact Address