8
13 «ùgbôn nítorí ìtìjú, ìyàwó máa ñ dúró sí ilé ækæ wæn. Gêgê bí obìnrin, inú mi bàjê pé ìyàwó máa dúró nínú ìbá«epö tí kò wù wôn nítorí èrò awujo nìkan. Mo rò pé inúnibíni ni èyí sí obìnrin. A sì tun gbôdö mô pé iru èrò yìí waye ni öpölæpö à«à míràn. Kìí «e à«à Yorùbá nìkan. Ìdí kéjì ti pëñtùká kò wôpö láàrin àwæn Yorùbá layé àtijô ní æmæ. O «eé«e pé inú æmæ máa bàjê bí òbí rë bá «e pëñtùká, nítorí náà tækætayà kìí kô ara wæn sílë láti jê ki inú æmæ wæn bàjê. Lóòótô ní pé pëñtùká máa ní èrè buburu fún öpölæpö æmæ, nítorí náà, àwæn òbí máa gbìyànjú láti rí önà àbáyæ fún wàhálà wæn dipo «i«e ìkösílë. Láyé àtijô, nigba ti tækætayà ba kæ ara wæn sílë, ìyàwó máa kuro ni ilé ækæ, nítorí náà o máa ñ «òrò fún ækæ lati ri æmæ wæn nítorí pé æmæ àti ìyàwó máa læ sí ibomíràn. Iru èrò àti ihuwasi yìí si tun wôpö lóde òní ni à«à Yorùbá àti ní à«à Amêríkà. Ìdí mìíràn tí ìkösílë kò fi wôpö láyé àtijô ni ojú«e ækæ láti pèsè owó oúnj÷ fún ìyàwó. Èyí ní nõkan lati «e pëlú æmæ nítorí pé itoju æmædé wôn púpö. Ìyàwó nílò owó púpö láti pèsè oúnj÷ òôjô fún æmæ wæn. Nínú à«à Yorùbá láyé àtijô, oju«e ækæ ní lati ní i«e lôwô. Obìnrin lè «e i«ê wæn, bii títà nõkan ní æjà, «ùgbôn ækæ máa ñ sábà ní ojú«e tó tobi jù. Ní öpö ìgbà, ækæ máa gbá owó jú ìyàwó læ. Ó jê àõfààní fún àwæn obìnrin láti ní ækæ. Fún idi yìí, ìyàwó tó fê kæ ækæ wæn sílë máa ñ pinnu láti dúró sínú ìgbéyàwó wæn. Ìdí kerin tí pëñtùká kò fi wôpö láyé àtijô ní ìfê. Ìfê jê idi ti gbogbo tækætayà ni àgbáyé kò fi ní ìkösílë. Ìyàwó àti ækæ tó fêràn ara wæn kò nílò láti kæ ara wæn sílë. Bi a ti ri tëlê nínú bébà yìí, orí«irí«i önà wa ti ækùnrin àti obìnrin máa fêràn ara wæn.

ibeyawo yoruba 2 · ìyàwó máa fi æwô si ori ækæ, wæn máa gbadura. Ìdílé ækæ máa «e nõkan kan náà ... Iru adura ti ìdílé máa ñ sæ da lori ësìn tækætayà

  • Upload
    lamque

  • View
    221

  • Download
    0

Embed Size (px)

Citation preview

13

«ùgbôn nítorí ìtìjú, ìyàwó máa ñ dúró sí ilé ækæ wæn. Gêgê bí obìnrin, inú mi bàjê

pé ìyàwó máa dúró nínú ìbá«epö tí kò wù wôn nítorí èrò awujo nìkan. Mo rò pé

inúnibíni ni èyí sí obìnrin. A sì tun gbôdö mô pé iru èrò yìí waye ni öpölæpö à«à

míràn. Kìí «e à«à Yorùbá nìkan.

Ìdí kéjì ti pëñtùká kò wôpö láàrin àwæn Yorùbá layé àtijô ní æmæ. O «eé«e

pé inú æmæ máa bàjê bí òbí rë bá «e pëñtùká, nítorí náà tækætayà kìí kô ara wæn

sílë láti jê ki inú æmæ wæn bàjê. Lóòótô ní pé pëñtùká máa ní èrè buburu fún

öpölæpö æmæ, nítorí náà, àwæn òbí máa gbìyànjú láti rí önà àbáyæ fún wàhálà wæn

dipo «i«e ìkösílë. Láyé àtijô, nigba ti tækætayà ba kæ ara wæn sílë, ìyàwó máa kuro

ni ilé ækæ, nítorí náà o máa ñ «òrò fún ækæ lati ri æmæ wæn nítorí pé æmæ àti ìyàwó

máa læ sí ibomíràn. Iru èrò àti ihuwasi yìí si tun wôpö lóde òní ni à«à Yorùbá àti ní

à«à Amêríkà.

Ìdí mìíràn tí ìkösílë kò fi wôpö láyé àtijô ni ojú«e ækæ láti pèsè owó oúnj÷ fún

ìyàwó. Èyí ní nõkan lati «e pëlú æmæ nítorí pé itoju æmædé wôn púpö. Ìyàwó nílò

owó púpö láti pèsè oúnj÷ òôjô fún æmæ wæn. Nínú à«à Yorùbá láyé àtijô, oju«e ækæ

ní lati ní i«e lôwô. Obìnrin lè «e i«ê wæn, bii títà nõkan ní æjà, «ùgbôn ækæ máa ñ

sábà ní ojú«e tó tobi jù. Ní öpö ìgbà, ækæ máa gbá owó jú ìyàwó læ. Ó jê àõfààní

fún àwæn obìnrin láti ní ækæ. Fún idi yìí, ìyàwó tó fê kæ ækæ wæn sílë máa ñ pinnu

láti dúró sínú ìgbéyàwó wæn.

Ìdí kerin tí pëñtùká kò fi wôpö láyé àtijô ní ìfê. Ìfê jê idi ti gbogbo tækætayà ni

àgbáyé kò fi ní ìkösílë. Ìyàwó àti ækæ tó fêràn ara wæn kò nílò láti kæ ara wæn sílë.

Bi a ti ri tëlê nínú bébà yìí, orí«irí«i önà wa ti ækùnrin àti obìnrin máa fêràn ara wæn.

14

Kìí «e pé gbogbo önà yìí ni ó da lori ìfê làkôkô. Lêhìn ti obìnrin ati ækùnrin ti mo ara

wæn dáadáa, wæn máa mô bí wæn bá fê ara wæn tàbí bi wæn kò bá fê fê ara wæn.

Nítorí náa, lêhìn àkókó díë tàbí àkókó púpö ó «eé«e pé ækùnrin àti obìnrin tó wa ní

ojú öna máa pinnu pé ìfê tó nípæn wa lara wæn tàbí pé ìfê kò si. Èyí jê idi ti ètò

ìgbéyàwó fifi æmæ lôkæ dara gan an ni. Ækùnrin àti obìnrin gbôdö gbé ìgbésë

ælægbôn kí wæn to «e ìgbéyàwó. Fun idi yìí pëñtùká kò wôpö láàárín àwæn Yorùbá

láyé àtijô.

Títí di ibi yìí, a ti sörö nípa iru ìgbéyàwó áyé àtijô mêta báyìí: fifi æmæ lôkæ,

jíjí ìyàwó gbé àti ìyàwó òrì«à. Iru ìgbéyàwó mêtêëta yìí kò wôpö mô láàárín àwæn

Yorùbá. Nítorí i«àn ësìn ìbàgbô àti ësìn Mùsùlùmí ni orílë-èdè Nàìjíríyà, ètò

ìgbéyàwó Yorùbá ti yípadà. Àyípadà tó nípæn jú láàárín ìgbéyàwó áyé àtijô àti ti

óde òní ní ó jê pé, kò wôpö fún ækæ láti ni ìyàwó jù òókàn læ. Láyé àtijô o wôpö fun

ækæ lati ni ìyàwó méjì tàbí meta tàbí merin. A ñ pé àwæn ìyàwó yìí ni ìyáálé.

»ùgbôn, iwa yìí kò wôpö púpö mô. Kodá, gêgê bí ofìn ìgbéyàwó oníbàgbô,

Mùsùlùmí àti kóòtù, ækæ kò gbôdö fê obìnrin mìíràn, afi ìyàwó nìkan. »ùgbôn,

Mùsùlùmí lè fê ju ìyàwó kan læ. Ìyàtö mìíràn ni pé alárinà àti ètò fifi æmæ lôkæ kò

«ëlë púpö mô. Lóde òní æmækùnrin yóo fúnrarë yan ìyàwó fê, æmæbìnrin yóo sí wà

ækæ tó bá wù ú fê. Æmækùnrin àti æmæbìnrin lè mô ara wæn láti önaköna. Nõkan

méjì yìí jê ìyàtö nla láàárín ìgbéyàwó láyé àtijô àti ti ìgbéyàwó lóde òní. A lè pin

ìgbéyàwó lóde òní si mêta: Ìgbéyàwó elësìn, ìgbéyàwó kóòtù àti ìgbéyàwó ìbílë.

¿ jê kí ñ kôkô sörö nípa ìgbéyàwó ìbílë. Lóde òní ìgbéyàwó àwæn Yorùbá

púpö máa ñ káràmásìkí à«à ìbílë díë nítorí pé à«à gidi ni à«à náà. Àwæn Yorùbá

15

kò fê pàdánù rë. Fún ìdí pàtàkì yìí, tækætayà máa böwæ fún à«à ìbílë læjô ay÷y÷

ìgbéyàwó wæn. Ìgbéyàwó ìbílë láyé ode òní jê àmónùmólà. Ësìn ìbàgbô,

Mùsùlùmí àti ìgbéyàwó kóòtù lè ni ipa nínú ìgbéyàwó ìbílë. Ay÷y÷ ìgbéyàwó to dà

à«à ìbílë àti ësìn pæ pö ní ilë Yorùbá lóde òní. O wôpö pé æjô kínni ay÷y÷

ìgbéyàwó tækætayà kan máa ñ fara à«à ìbílë mô. Ní báyìí, æjô kéjì ay÷y÷ à«à

Yorùbá máa ñ saba jê ìgbéyàwó ti ësìn tækætayà.

Nítorí náà, lêhìn ti æmæbìnrin àti æmækùnrin ti pinnu láti «e ìgbéyàwó, ÷bí

wæn máa b÷r÷ sí «e ilana fun ay÷y÷. Ìdílé mejeeji máa ni ipa púpö nínú ìgbéyàwó

ìbílë. Dandan ni kí ìdílé ækæ ati ìdílé ìyàwó wa ni jokòó ni ibi ìgbéyàwó ìbílë

Yorùbá. Bi ÷bí tækætayà «e lôwô tó, bêë ni àsè ay÷y÷ náa «e máa tobi tó. Bí

tækætayà bá jê olówo, wæn máa ní ay÷y÷ ñlá pëlú oúnj÷ púpö, òti púpö àti alejo

púpö. Bi ènìyàn lôwô gan, wæn nawo púpö. Bí mekunnu ni, tækætayà máa ní ay÷y÷

tó kere láìsi ohun amáyéd÷rùn púpö. Læjô ay÷y÷ ìgbéyàwó, ìyàwó máa mura ní

a«æ dáadáa nilé. Àwæn örê ìyàwó àti obìnrin-ilé wæn máa ran ìyàwó lôwô. Ìyàwó

máa we gele to ba kaba rë mu. Ó sì tun máa wo ègbà ærùn, y÷tí àti ëgbà æwô.

Ìmúra ìyàwó læjô ìgbéyàwó máa

lewa gan-an ni. Ækæ àti ìyàwó

máa wo iru a«æ kan náà lati fi han

pé tækætayà ni wæn. Bí ó bá wù

÷bí ækæ, gbogbo wæn máa wo iru

a«æ kan náà. Gbogbo ÷bí ìyàwó

sì tun lè wo a«æ kan náà bí ó bá Ækæ ñ rin sí ibi ay÷y÷ pëlú àwæn örê wæn.

16

wù wæn. Èyí fi i«okan ÷bí han. Púpö ni àwæn alejo ni ay÷y÷ ìgbéyàwó ìbílë máa ñ

wo a«æ òké Yorùbá. Nigba ti ìyàwó ti múra tan, òun àti örê wæn máa lo si ibi ay÷y÷.

Ækæ àti ìyàwó máa ñ dé sí ibi ay÷y÷ ní àkókó ötöötö pëlú ÷gbê örê àwæn. Ni àkókó

ti ìyàwó àti ækæ bá de, örê wæn, ÷bí wæn àti gbogbo alejò máa ñ korin. Wæn sì tun

máa ñ jo.

Ay÷y÷ máa ñ sábà «ëlë nita láb÷ teenti nítorí pé oorun máa ñ mu púpö nilë

Yorùbá. Ay÷y÷ ìgbéyàwó ìbílë ní ikójæ díë. ¿ní tí a ñ pé ni alága máa ñ sörö fún

“microphone” nípa nõkan tó ñ wáyé.

Alága náà sì tun máa ñ korin, gbadura

púpö fun tækætayà àti sæ ìtàn nípa

tækætayà. Alága méjì ní ó sábà máa ñ

wa ni ìgbéyàwó ìbílë, ækan fún ìdílé

ìyàwó èkejì fún ìdílé ækæ. Àwọn alága

ìdúró àti alága ìjókòó ní. Àwæn alága

jê ènìyàn ti ÷bí tækætayà mô dáadáa. Ojú«e nlá ni i«ê alága nítorí pé nõkan púpö tó

«e pàtàkì máa «ëlë ni ay÷y÷ ìgbéyàwó. Ay÷y÷ ìgbéyàwó ìbílë lè gun wákàtí púpö

nítorí pé àwæn alejo máa ñ

jeun, wæn máa ñ jo, wæn máa

ñ gbadura, wæn máa fún

tækætayà ni ëbùn. O «e pàtàkì

pé ìdílé ækæ àti ìdílé ìyàwó «e

adura fún tækætayà. Ìdílé

Alága ìdúró jê obìnrin tó ni “microphone” læowô. Wæn ñ korin láti ki àwæn alejo.

Ækæ ìyàwó, àbúrò wæn àti àwæn örê wæn ñ döbálë niwaju ìdílé ækæ àti ìyàwó.

17

méjèèjì máa jokòó nínú aga láb÷ teenti. Ækæ máa döbálë niwaju ìdílé méjèèjì, ìdílé

ìyàwó máa fi æwô si ori ækæ, wæn máa gbadura. Ìdílé ækæ máa «e nõkan kan náà

fun òun. Iru adura ti ìdílé máa ñ sæ da lori ësìn tækætayà. Nigba ti ìyàwó ba kúnlë

niwaju ìdílé tàwn ati ti ækæ wæn tó ñ jokòó, nõkan kan náà máa wáyé. Ækæ àti

ìyàwó máa böwö fún òbí wæn gan-an ni ni àkókó yìí. Ìyàwó tun máa kúnlë fún ækæ

wæn. Èyí jê ami pé ìyàwó ni iböwö fún ækæ wæn. Ìyàwó kò nílò láti kúnlë fún ækæ

wæn ní æjô iwaju nítorí ækàn ni wæn nísinsìnyí.

Nõkan ti ay÷y÷ ìgbéyàwó

ìbílë fi han nípa à«à Yorùbá ni pé

÷bí pon dàndàn gan-an ni. Fún

àwæn Yorùbá, ìgbéyàwó jê

ìbá«epö láàárín ìdílé ækæ àti ìyàwó.

Èyí yàtö si à«à mìíràn. Gêgê bí

à«à Yorùbá, ìgbéyàwó kìí jê

ìbá«epö tækætayà nìkan. Nítorí náà ìdílé méjèèjì gbôdö fæwô sí ìbá«epö tækætayà.

¿ jê ki ñ sörö nípa ìgbéyàwó elésin báyìí. Ësìn méjì tó lokiki jú ni ilë Yorùbá

jê ësìn ìbàgbô àti ësìn Mùsùlùmí. Nítorí àwæn ìbàgbô ësìn yìí méjèèjì yàtö si ara

wæn, ìgbéyàwó sì tun yàtö. A máa yà sisörö nípa ìgbéyàwó ësìn ìbàgbô àti ësìn

Mùsùlùmí sôtö.

Ìgbéyàwó ësìn ìbàgbô wôpö ni ilë Yorùbá lóde òní. Bi mo «e sæ tëlê, ó

wôpö fun tækætayà láti ni ìgbéyàwó ìbílë àti ìgbéyàwó onígbàgbô. Nítorí náà,

nõkan tí a máa ñ pé ni ìgbéyàwó ònígbàgbô jê ase tó máa ñ wáyé ni «ôö«i. Ní iru

Ìyàwó ñ kúnlë fún ækæ wæn láti fi iböwö rë han.

18

ìgbéyàwó yìí, tækætayà lè wo a«æ Òyínbó. Ìyàwó máa ñ wo kaba funfun tó gun

gan-an ni. Ækæ máa ñ wo “tuxedo”. Ìyàwó máa ñ yan àwæn obìnrin tó máa wa nínú

÷gbê wæn. Obìnrin ÷l÷gbê yìí máa jê örê tímôtímô ìyàwó tàbí ÷bí wæn. Gbogbo

obìnrin yìí máa wo kaba alawo kan náà. A ñ pé àwæn obìnrin yìí ni “bride’s maids”

ni èdè Gêësì. Ækæ si tun máa yan ÷gbê ækùnrin tí a ñ pé ni “groom’s men” ni èdè

Gêësì. Laaro æjô ìsìn ìgbéyàwó yìí, tækætayà àti àwæn alejo máa ñ lo si «ôö«i.

Gbogbo alejo máa jokòó. ¿gbê ìyàwó àti ÷gbê ækæ máa jokòó nibi kan ötöötö.

Lêhìn èyí, ìsìn máa bërë. Alufaa máa pe ìyàwó àti ækæ ìyàwó kí wæn bô síwájú.

Wæn máa dìde láti «e ibura ìfê títí di æjô ikú, ìbá jê nínú didun àti aidun. Ækæ àti

ìyàwó máa jê ëjê pé wæn kò ní ní fê ènìyàn míràn. Lêhìn náà oníwàásù máa béèrè

bi ÷nikeni mæ idi kan ti kò fi y÷ kí wæn da àwæn méjèèjì yìí pö ni ìgbéyàwó. Bí kò bá

si, oníwàásù máa so fún tækætayà pé wæn le paaro òrùka wæn, ki wæn fí bæ ara wæn

lôwô. Òrùka jê àmì pé tækætayà máa fi gbogbo ìgbésí ayé wæn fún ara wæn. Ó jê

àmì ìgbéyàwó tó wôpö lóde òní ní àgbáyé. Lêhìn náà ìsìn ti tan. Tækætayà àti

àwæn alejo máa lo sí ibi tàbí ilé kan fún ay÷y÷ ìgbéyàwó. Wæn máa gé kéèkì nlá.

Öpölæpö ènìyàn ni yóó fún tækætayà ni ìmöràn, ìkìlö àti àdúrà, wæn yóó si fún wæn

ni orí«irí«i ëbùn. Báyìí ni àwæn Yorùbá «e ìyàwó onígbàgbô.

‘Yìgì’ jê örö fún ìgbéyàwó gêgê bí ësìn Isíláàmù. Nigba ti àwæn òbí rò pé

æmæbìnrin wæn tí dàgbà, wæn máa múrá fún yìgì rë. Ækæ gbôdö sanwó fún ìyàwó

wæn. Æmækùnrin Mùsùlùmí lè ni ìyàwó merin, «ùgbôn èyí kò rærùn nítorí pé òun

gbôdö nífê kan náà fún ìyàwó köökan. Æmæbìnrin máa gbe pëlú òbí wæn titi di æjô

ay÷y÷ ìgbéyàwó wæn. Ní æjô tí obìnrin àti ækùnrin Mùsùlùmí máa «e yìgì, obìnrin

19

yóo wæ a«æ funfun. ¿lëêrì merin gbôdö wa ni ay÷y÷ tækætayà Mùsùlùmí láti sæ pé

otito ni ifë láàárín wæn. Ìyàwó máa ñ «e nõkan tò dabi à«ejáde ilé-ëkô. Àlùfáà máa

ñ kô ìyàwó ni kéwú. Ìyàwó kò ri ækæ rë fun àkôkô púpö, títí de ó ti fi yege.

Ìgbéyàwó kóòtù ni èyí tí àwæn ènìyàn máa ñ «e ni kóòtù nilé ijæba ìbílë.

Obìnrin àti ækùnrin máa «e ìgbéyàwó kóòtù fún öpölæpö idi. Bí tækætayà bá fê «e

ìgbéyàwó kíakíá kí ökan nínú wæn ti læ sí ìdálë fún æjô pípê díë, wæn máa ñ «e é.

Bí wæn bá fê «e ìgbéyàwó wôôrôrô, làísi ìmö ènìyàn púpö. O wôpö fún àwæn

ömöwé láti «e ìgbéyàwó yìí. Ækùnrin àti obìnrin ti kò gbàgbô nínú ësìn kan kan sì

tun lè «e ìgbéyàwó kóòtù nítorí pé kò da lori ësìn rárá. Láti «e ìgbéyàwó kóòtù,

tækætayà máa læ gba ìwé à«÷ méjì. Èkínní ní ìwé à«÷ ìgbóná-ìgbooru. Lêhìn ti

tækætayà ti kô orúkæ wæn sílë, wæn lè «e ìgbéyàwó lôjô náà. Èkéjì ní ìwé à«÷ ojú-

kò-kán-mi. Fôömù yìí jê kí tækætayà máa dúró æjô mækànlélógún kí wæn tó «e

ìgbéyàwó. Èté fôömù yìí ní ki ijæba lè rí bí ÷ni rò pé kò yê kí ækùnrin àti obìnrin yìí

«e ìgbéyàwó. Ijæba máa t÷ ìkéde ìmúra ìgbéyàwó tækætayà náà jade. Bí ÷nikeni

kò ba sæ nõkankan lêhìn æjô mækànlélógún, ækùnrin àti obìnrin yìí lè «e ìgbéyàwó

kóòtù. Æmæbìinrin àti æmækùnrin kò nílò ìyöñda òbí kankan láti «e ìgbéyàwó yìí,

«ùgbôn, æmæbìnrin ní láti tó æmæ ædún méjìdínlógún.

Ìgbéyàwó kóòtù kò dùn púpö nítorí pé, kò fi ààyè gba ay÷y÷ púpö bíi ti ìbílë

tàbí ësìn. Tækætayà máa mú æjô kan læ sí kóòtù. Örê tækætayà lè wà níbë.

Tækætayà máa wæ a«æ dáradára. Adájô máa «ètò ìgbéyàwó. Tækætayà máa búrá

pé àwæn yóo fêràn ara àwæn títí di æjô iku. Ækæ máa fi òrùka bæ ìyàwó rë lôwô.

20

Eleyìí dabi ìgbéyàwó ònígbàgbô. Lêhìn náà, wæn lé læ sí ibi àsè. Wæn lè ní àsè bi

gbogbo àwæn àsè ìgbéyàwó míràn, bi ay÷y÷ ìbílë.

Àwæn Yorùbá máa ñ pa òwe pé ‘bí a ti «e nilé, ÷ni èèwæ ni.’ Ni ibomìíràn, bí

ó tílë jê pé à«à Yorùbá nípa ìgbéyàwó yàtö sí à«à míràn, ó ní àwæn ohún tí ó dára

àti àwæn atún«e köökan. Lèrò mi, ìgbéyàwó Yorùbá áye àtijô ni àõfààní àti èèbu.

Önà ti æmækùnrin àti æmæbìnrin mæ ara wæn wù mi nítorí pé wæn máa gba iranlôwô

púpö láti òbí wæn àti alárinà. O dabi pé «i«e ìgbéyàwó rærùn láyé àtijô ju lóde òní læ

nítorí pé ènìyàn púpö wa tó fê ran æmækùnrin àti æmæbìnrin lôwô. Nõkan to ba inú

mi jê ni ipo àlòkù obìnrin. Ñ kò fê ki obìnrin tó kæ ækæ wæn sílë lè gba örö buruku

awujo. »ùgbôn, mo rò pé ìgbéyàwó ìbílë lóde òní dára gan-an ni. Mo fêràn bi

àwæn Yorùbá máa ñ böwö fún à«à ìbílë wæn àti ësìn wæn. Mo fê læ sí ay÷y÷

ìgbéyàwó Yorùbá ni æjô iwaju.

Mo ti «e ìföröwánilênuwò púpö pëlú àwæn olúko mi nípa ìgbéyàwó àwæn

Yorùbá. Mo fê dupe fún iranlôwô wôn. Àwæn olúko mi si tun ti «e atun«e púpö si

bébà mi. Láìsí idúróti wæn, kíkô bébà yìí kìí «eé«e. Bébà mi kò ju báyìí lo. ¿ «e

gan-an ni.