19

OGBOJU ODE NINU IGBO IRUNMOLE€¦ · aforesunise, awa a ma wo yin, oju yin ko gbe ibikan, e n ba hilahilo kiri, awon tin won ba ri je ninu yin, nwon a ma wa ipo ola, nwon a fe ma

  • Upload
    others

  • View
    43

  • Download
    7

Embed Size (px)

Citation preview

Page 1: OGBOJU ODE NINU IGBO IRUNMOLE€¦ · aforesunise, awa a ma wo yin, oju yin ko gbe ibikan, e n ba hilahilo kiri, awon tin won ba ri je ninu yin, nwon a ma wa ipo ola, nwon a fe ma
Page 2: OGBOJU ODE NINU IGBO IRUNMOLE€¦ · aforesunise, awa a ma wo yin, oju yin ko gbe ibikan, e n ba hilahilo kiri, awon tin won ba ri je ninu yin, nwon a ma wa ipo ola, nwon a fe ma

OGBOJU ODE NINU IGBO IRUNMOLE

Page 3: OGBOJU ODE NINU IGBO IRUNMOLE€¦ · aforesunise, awa a ma wo yin, oju yin ko gbe ibikan, e n ba hilahilo kiri, awon tin won ba ri je ninu yin, nwon a ma wa ipo ola, nwon a fe ma

AKARA OGUN ATI AWON OBI RE

1a. Tani o so oro yii

“Mu ohun ikowe re, beresi iko itan ti emi o so wonyi sile,

mase fi I sile di ojo miran ki anfani re ki o ma ba re o

koja. Emi papa ki ba ti wa loni bikosepe mo nronu ehin

ola, nitori eru nba mi ki nmaba lo ku ni ai-rotele, ki itan

na si ku pelu mi, sugbon bi mo ba so o fun o loni, ti iwo

ba si ko o sile daradara, bi ojo mi ba tilw pe ti mo ku,

awon omo araiye ko ni gbagbe mi”.

b. Kini ise awon nkan wonyii ninu ise Ode sis

-Onde

- Ado

-Ato

c. Se apejuwe ni soki, iyato ti o wa laarin Igbe ode ati ise

agbe

d. Se alaye ni soki iku ti o pa Iya Akara Ogun

Page 4: OGBOJU ODE NINU IGBO IRUNMOLE€¦ · aforesunise, awa a ma wo yin, oju yin ko gbe ibikan, e n ba hilahilo kiri, awon tin won ba ri je ninu yin, nwon a ma wa ipo ola, nwon a fe ma

2a.Di awon alafo wonyii:

Beni mo ri ehin okunrin na sugbon nko gbodo yo jube lo

nitoripe nko mo ibiti mo wa rara. Ohun ti mo ko se lehin

ti mo pa a tan nip e mo wo inu iho re ni lo, nigbati mo

side inu re tan oniruru ohun alumoni aiye yi ni mo ba –

awon bi ileke, lagidigba ati awon aso bi

____________,__________,______________,________

_________ ati awon ___________ ti o gbe hau tin won

si lu ni olupopo. Motun ri oniruru fila awon bi

____________, ____________ ati ______________, mo

si ri ade meta ti a fi ileke se, bi Oba ba de won ko si eniti

o le ri oju Oba naa, ileke yio bo o loju.

b. “E maser o pe mo je tan yin je rara, mo fe ki e mo pe

ko si nkan ti mo gba lowo okunrin na lati ojo ti o ti so pe

on fe mi, se eniti o ba n ri mi lode yio ma ro pe on lo n se

nkan gbogbo fun mi! iro ni, bi o ti lowo to ni ko le fi

epinnin ba enikeni sire, opelope ejika ti ko jeki ewu k

obo. Opelope Iya mi ti ko jeki ebi yo mi loju je, bi ko ba

si ti iya mi emi iba si ma rin ni igboro ilu bayi, esinsin

iba ma kun mi, aja iba ti ma gbo mi. O lawun ju aja ti o

po onje sile tan ti o tun npada kooje. Bi esi ti n wo ni o

Page 5: OGBOJU ODE NINU IGBO IRUNMOLE€¦ · aforesunise, awa a ma wo yin, oju yin ko gbe ibikan, e n ba hilahilo kiri, awon tin won ba ri je ninu yin, nwon a ma wa ipo ola, nwon a fe ma

gbadun fari to nkan. Igbati o ba jaja lo si ilu onilu ti o ba

ri bi awon ayaba tin se tan a sese da a ma se kutakuta ni

on nfe ge aso fun mi; oloriburuku, olorunburuje afi bi e

pa a dandan. Ona pipa re na si ni yi – ko ju kekere lo –

bi o ba ti di oru oni ti gbogbo eniyan ba ti sun tan ngo

dide, ngo silekun afin sile, ki e yan awon akoni okunrin

merin ti awon ti ida ki won wole; iyara ti e ba ri ti ferese

re ba si sile ki e wo o, ibe ni Oba wa, enikeni ti e ba si ri

ni ibe ni oba wa. Enikeni ti e ba si ri nibe, pipa ni ki e

pa a?

-Kini ohun ti o mu iru oro yii wa

-Tani o so oro yii

-Awon wo ni ohun so oro naa fun

-Iru ete wo ni obinrin naa da.

Page 6: OGBOJU ODE NINU IGBO IRUNMOLE€¦ · aforesunise, awa a ma wo yin, oju yin ko gbe ibikan, e n ba hilahilo kiri, awon tin won ba ri je ninu yin, nwon a ma wa ipo ola, nwon a fe ma

IGBA EKINI AKARA OGUN NINU IGBO

IRUNMALE

1a. Ta ni oro yii n gbiyanju lati sapejuwe “Nigbati mo ti

wa ni bi omo odun mewa ni mo ti nba baba mi lo si igbe

ode, nigbati mo si ti to omo odun meedogun, ni mo ti da

ibon ni fun ara mi. Baba mi ku nigbati mo di omo odun

medogbon gere; nigbati o si ku yi, ati owo ti o ni ni ati

ogun ti o ni ni, ogun ni mo fi gbogbo won je ki o to ku

pelu, mo tin pa erin, owo mi si ti n ba efon, sasa eranko

ni ibon mi ko tile ti ipa.

b. Tani Olori-igbo

c. Olori-igbo!

Olori Igbo !

Iwo ni oloja Iwin

Mo ni iwo ni oloja iwin

Ko si Oloja to dabi re

Apa omo araiye ni iwo fin je iyan

Page 7: OGBOJU ODE NINU IGBO IRUNMOLE€¦ · aforesunise, awa a ma wo yin, oju yin ko gbe ibikan, e n ba hilahilo kiri, awon tin won ba ri je ninu yin, nwon a ma wa ipo ola, nwon a fe ma

Genge aiya won ni iwo fin je oka

Atari won ni iwo fin mu eko

Kini omo araiye maa fi o se!

Olori igbo o!

Iwo nfi ori rin ni n dan?

Mo ni iwo n fi ori rin ni ndan?

Nitori oju re n be ni idi re

O ntanna sese

Olori igbo o!

Are nse o ni dan?

Tabi etiri ti iwo ko le jade?

Gbogbo wa n reti re?

- Koko oro inu ewi yii ni

- Kini ise apetunpe oro n se ninu ewi yii

- Daruko marun ninu koseemani amuye ewi

apileko

Page 8: OGBOJU ODE NINU IGBO IRUNMOLE€¦ · aforesunise, awa a ma wo yin, oju yin ko gbe ibikan, e n ba hilahilo kiri, awon tin won ba ri je ninu yin, nwon a ma wa ipo ola, nwon a fe ma

- Ohun meji ti o se Pataki ninu ewi ni

- Sa awon ewa ede ati oro ijinle ninu ewi yii

2a. E:-:-:-:-:-:-e! ina ti mbe lodo ese, owo omo araiye ni

o. Niggati o wi bayi tan gbogbo won gbe oju soke; won

si ri mi. A! onijo njo, alayo nyo, nwon ndamuso nitori

mi, nwon nfe pa mi je. Ibiti now tin pa ero bi awon yio ti

se re mi lule ni mo ti ranti ogun mi kan bayii,

- Tani o nkigbe ina, ina, ina

- Tani won n wo lo’ke

- Kini eniti won n wo loke se lati le gba ara re la

b. Bayi ni enyin omo araiye ma n se, enyin

aforesunise, awa a ma wo yin, oju yin ko gbe ibikan,

e n ba hilahilo kiri, awon tin won ba ri je ninu yin,

nwon a ma wa ipo ola, nwon a fe ma jaiye oba, nwon

a gbagbe pe omo ika omo won ko dogba. Gegebi iwa

eda yin pelu, okan yin ki bale, eniti inu re ba dun

loni, awon eniyan re to ni simi lola; o ni iku, ola

arun, oni ija, ola airoju, oni ekun, ola ibanuje; ni

omo araiye ma n ba kiri, nigbati a wa ba si ronu nipa

Page 9: OGBOJU ODE NINU IGBO IRUNMOLE€¦ · aforesunise, awa a ma wo yin, oju yin ko gbe ibikan, e n ba hilahilo kiri, awon tin won ba ri je ninu yin, nwon a ma wa ipo ola, nwon a fe ma

tiyin, anu yin a se wa, awa a ma sokun nitori yin,

ikun a si ma yo ni imu wa, sugbo dipo ki eyina wa fi

eni wa tan wa, e ma fi ikun imu wa bu wa.

Tani o so oro yii

Tani oro naa n bawi

3a. Fi ami si ori awon oro wonyii

i. Igbo irunmale

ii. Merindinlogun

iii. Agbako

iv. Mariwo

v. Agiliti

vi. Kukute

vii. Edumare

viii. Hilahilo

Page 10: OGBOJU ODE NINU IGBO IRUNMOLE€¦ · aforesunise, awa a ma wo yin, oju yin ko gbe ibikan, e n ba hilahilo kiri, awon tin won ba ri je ninu yin, nwon a ma wa ipo ola, nwon a fe ma

xi. Tibinutibinu

x. Alailanu

Page 11: OGBOJU ODE NINU IGBO IRUNMOLE€¦ · aforesunise, awa a ma wo yin, oju yin ko gbe ibikan, e n ba hilahilo kiri, awon tin won ba ri je ninu yin, nwon a ma wa ipo ola, nwon a fe ma

AKARA OGUN ATI LAMORIN

1a. Tani ogboju Ode ba pade ninu Igbo Irunmale

b. Nibo lo ti mon

c. Tani o n je Ijanba

d. Oro wo ni Lamorin so nigba ti won foju kan

Lamorin

2a. Tani o so oro yii ati wipe tani oro naa nbawi

“E! ori mi, e! ori mi, awon kokoro sisanra yi logba;

‘E! ori mi, e! ori mi!

b. Tani o beere ibeere yii

“Nibo ni iwo ti wa nibo ni iwo sin lo? Eredi re ti iwo

fi n wadi mi?

Tani o fo esi yii

c. Fi ami si ori awon oro wonyii:

i. Lamorin

Page 12: OGBOJU ODE NINU IGBO IRUNMOLE€¦ · aforesunise, awa a ma wo yin, oju yin ko gbe ibikan, e n ba hilahilo kiri, awon tin won ba ri je ninu yin, nwon a ma wa ipo ola, nwon a fe ma

ii. Tembelekun

iii. Idarudapo

iv. Sarasara.

v. Ramumu

Page 13: OGBOJU ODE NINU IGBO IRUNMOLE€¦ · aforesunise, awa a ma wo yin, oju yin ko gbe ibikan, e n ba hilahilo kiri, awon tin won ba ri je ninu yin, nwon a ma wa ipo ola, nwon a fe ma

AWON ERO OKE LANGBODO

1a. Di alafo wonyii:

Iranse Oba kan lo dede wole ti o wi fun pe Oba n pe

mi. Eleyi ya mi lenu mo si dide mo wo ewu mi, mo de fila

________________ mo si wo sokoto____________mi,

mo mura o di ile Oba

b. Daruko awon Ogboju Ode ti won tele Akara Ogun

lo si Langbodo.

c. Tani o soro yii ati wipe tani o n ba wi

“Kini se to be o ko ni? Oran wo ni mo da tobe? Ese

wo ni mo se to be? Ona wo ni mo gba fi se yin? Eri

okunrin miran pelu mi ni? E gbo pe mo nsoro aidara si

yin ni? Mo nhu wa ole ni? Nko wa onje lakoko ni? Nko

fife han to ni? E gbo pe mo nja kakiri bi? E gbo pe oro

omo ita nti enu mi jedebi? Mo nna inakuna bi? Mo n se

aseju fari bi? Tabi mo nrin irin idoti ni ndan? Mo nhu

iwa aibikita si yin ni ndan? Nko gboransi yin lenu ni

ndan? Tabi nko tile mo ile itunse? Tabi nko mo alejo

itoju ni? Tabi nko mo ajo yin se to? Tabi nko ti le mo esi

Page 14: OGBOJU ODE NINU IGBO IRUNMOLE€¦ · aforesunise, awa a ma wo yin, oju yin ko gbe ibikan, e n ba hilahilo kiri, awon tin won ba ri je ninu yin, nwon a ma wa ipo ola, nwon a fe ma

oro ni? Tabi nko mo ajo yin se to? Tabi nko ran yin lowo

to ni ibi ise yin ni.

Page 15: OGBOJU ODE NINU IGBO IRUNMOLE€¦ · aforesunise, awa a ma wo yin, oju yin ko gbe ibikan, e n ba hilahilo kiri, awon tin won ba ri je ninu yin, nwon a ma wa ipo ola, nwon a fe ma

IGBA EKEJI AKARA OGUN NINU IGBO

IRUNMALE

1. Pin awon oro wonyii si Silebu, ki o si salaye ihun

okookan won

i. Omoluabi

ii. Losangangan

iii. Danindanin

vi. Tiyanutiyanu

v. Werewere

vi. Ehinkule

vii.Olorun buruja

viii.Epinni

x. Jagudapali

2a. Kini idahun eniti o ba soro

Page 16: OGBOJU ODE NINU IGBO IRUNMOLE€¦ · aforesunise, awa a ma wo yin, oju yin ko gbe ibikan, e n ba hilahilo kiri, awon tin won ba ri je ninu yin, nwon a ma wa ipo ola, nwon a fe ma

b. Nisoki so akitiyan awon ode wonyii ninu igbo

irunmale

- Akara Ogun

- Kako

- Imodoye

- Olohun Iyo

- Elegbe-Ode

- Efoiye

- Aramada-Okunrin

c. Tani o so oro yii:

“Enyin ara ilu wa gbogbo, e seun ti e wa lati wow a loni.

E hu iwa bi omo enia, e se bi omoluwabi si wa; e mu ki

ori way a, e mu ki aiya wa ba le, e mu ki okan wa si si

irin ajo wa. Bi ko ba si ohun ti o se ese, ese ki ise, bi ko

ba ni idi e ko ni dede se bayii ri wa. Gbogbo awa ti e n

woyii, Oke Langbodo ni a n lo, nitori ilu wa yin a si ni.

Ajo ki idun titi ki a ma ranti ile wa. Bi ilu eni kere ti o

Page 17: OGBOJU ODE NINU IGBO IRUNMOLE€¦ · aforesunise, awa a ma wo yin, oju yin ko gbe ibikan, e n ba hilahilo kiri, awon tin won ba ri je ninu yin, nwon a ma wa ipo ola, nwon a fe ma

dabi ite eiye, ilu eni ni ilu eni, ibi ilu eni re ehin ti oju

awon olugbe re ko la rara, ilu eni ni ilu eni, awon onilu

ni si ise ilu, awon ni iso ilu idoti di mimo, awon ni si iso

ilu kekere din la. Sugbon enikeni ti o ba wipe ilu on ki

idr t’on mo, gongosu enia ni.

3a. Ni oro kukuru, so iriri awon Ogboju ode ninu ilu

awon eiye

b. “Tani enyin wonyii? Nibo ni e ti wa? Nibo ni e si n lo?

Dajudaju ole ni yin, ami olosa mbe niwaju yin, nitorina e

se giri, ki Onibante san ibante; ki onisokoto fun sokoto,

ngo han yin lemo loni, ise meta ni e o se fun mi, bi e ko

ba si le se won, pipa ni ngo pa gbogbo yin je.

Tani o so oro yii?

c. Tani were-orun

d. Awon Ode Akoni melo ni won pa ni ilu awon eye.

e. Di alafo yii

Page 18: OGBOJU ODE NINU IGBO IRUNMOLE€¦ · aforesunise, awa a ma wo yin, oju yin ko gbe ibikan, e n ba hilahilo kiri, awon tin won ba ri je ninu yin, nwon a ma wa ipo ola, nwon a fe ma

_____________________ ki iwe; ewoni

_________________ oju re dabi ebi eniti o orun re dabi

ara opolo eri aiyebaiye si le moo, odudu bi ose ekolo, ejo

ati ________________ ni imi jade lenu re bi o ba n soro,

o n a si ma je won bi onje nigbati ebi ba de sii.

Page 19: OGBOJU ODE NINU IGBO IRUNMOLE€¦ · aforesunise, awa a ma wo yin, oju yin ko gbe ibikan, e n ba hilahilo kiri, awon tin won ba ri je ninu yin, nwon a ma wa ipo ola, nwon a fe ma

OJO EKEJI ATI OJO EKEJE LODO

IRAGBEJE NI ILU OLOJULEMEJE

1a.Ogboju ode melo ni won de odo iragbeje

b. Awon eko wo ni won riko lodo Iragbeje

c. Ni soki so itan kiniun ati awon eranko yooku

d. Se akosile eko ti itan na ko wa

e. Daruko awon eda ti o wa ninu itan na.