1
Iwadi Nipa Eniyan Ati Ilera Won Ni Odun 2013 2013 Nigeria Demographic and Health Survey Ibisi Okookan ninu awon obinrin ile Naijiria ni omo marun ati aabo (5.5). Ibisi ni ila iwo oorun Afirika wa laarin omo merin ni orile ede Ghana si mejo ni orile ede Niger. Ilera abiyamo Bii ibimo merin ninu mewa ni o ni iranlowo osise eto ilera. Ifeto somo bibi Ida meedogun ninu ogorun pere lo lo eyikeyi ninu eto ilana ifeto somo bibi. Lilo ilana fifi eto somo bibi wa laarin ida meta ninu ogorun ni ila oorun ariwa si ida mejidinlogbon ni iwo oorun gusu. Gbigba abere ajesara Gbigba abere ajesara ti gberu si ni ile Naijiria. Okan ninu omo merin ti o je osu mejila si metalelogun ni o gba gbogbo abere ajesara. © Abt Associates Nigeria/PATHS2 Project Apapo ibisi ni awon orile ede iwo oorun Afirika Ibisi fun obinrin kan laarin odun meta siwaju iwadi naa Ghana 2008 DHS 5.0 4.0 5.0 4.9 Benin 2011-12 DHS Cote d’Ivoire 2011-12 DHS Senegal 2010-11 DHS Sierra Leone 2008 DHS Liberia 2007 DHS Nigeria 2013 DHS Burkina Faso 2010 DHS Mali 2006 DHS Niger 2012 DHS 5.1 5.2 5.5 6.0 6.6 7.6 Bi lilo ilana ifeto somo bibi se gbile si ni elekunjekun Nigeria 15% Ida ninu ogorun awon obinrin ti o wa ni ile oko lowolowo ti ojo ori won wa laarin odun meedogun si mokandinlaadota ti won n lo eyikeyi ninu ilana ifeto somo bibi 10-25% >25% <10% North East 3% North West 4% North Central 16% South West 38% South East 29% South South 28% BCG DPT 3 Polio 3 Bi eto abere ajesara se n lo si 48 2003 NDHS 2008 NDHS 2013 NDHS 51 50 21 38 35 29 54 39 Ida lona ogorun awon omode ti o je osu mejila si metalelogun ti o gba abere ajesara Measles All None 36 42 41 13 25 23 27 21 29 Iku omode Isiro se afihan wiwa sile gbogbo ipele iku omode lati odun 2003. Bi iku omode se n lo si Ida lona egberun iku lori awon omo ti a bi laaye 2008 NDHS Iku omo ti ko pe odun kan 75 69 128 Iku omo ti ko pe odun marun 2013 NDHS 157 201 100 2003 NDHS Iku omo ti ko pe osu kan 40 37 48 Iranlowo lasiko ibimo *Ida mejidinlogoji ibimo ni o ni iranlowo osise eto ilera. Onise ilera agbegbe 2% Oluranlowo noosi/agbebi 3% Dokita 10% Noosi/agbebi 25% Agbebi ibile 22% Ibatan/elomiran 23% Ko si enikankan 13% Don’t know 1% *Osise eto ilera je dokita, noosi, agbebi, ati oluranlowo noosi/agbebi. © 2012 Akintunde Akinleye-NUHRI, Courtesy of Photoshare

Iwadi Nipa Eniyan Ati Ilera Won Ni Odun 2013 2013 Nigeria ...Iwadi Nipa Eniyan Ati Ilera Won Ni Odun 2013 2013 Nigeria Demographic and Health Survey Ibisi Okookan ninu awon obinrin

  • Upload
    others

  • View
    6

  • Download
    0

Embed Size (px)

Citation preview

Page 1: Iwadi Nipa Eniyan Ati Ilera Won Ni Odun 2013 2013 Nigeria ...Iwadi Nipa Eniyan Ati Ilera Won Ni Odun 2013 2013 Nigeria Demographic and Health Survey Ibisi Okookan ninu awon obinrin

Iwadi Nipa Eniyan Ati Ilera Won Ni Odun 20132013 Nigeria Demographic and Health Survey

Ibisi

Okookan ninu awon obinrin ile Naijiria ni omo marun ati aabo (5.5). Ibisi ni ila iwo oorun Afirika wa laarin omo merin ni orile ede Ghana si mejo ni orile ede Niger.

Ilera abiyamoBii ibimo merin ninu mewa ni o ni

iranlowo osise eto ilera.

Ifeto somo bibi

Ida meedogun ninu ogorun pere lo lo eyikeyi ninu eto ilana ifeto

somo bibi. Lilo ilana fifi eto somo bibi wa laarin ida meta ninu

ogorun ni ila oorun ariwa si ida mejidinlogbon ni iwo oorun gusu.

Gbigba abere ajesara

Gbigba abere ajesara ti gberu si ni ile Naijiria. Okan ninu omo merin ti o je osu mejila si metalelogun ni o gba gbogbo abere ajesara.

© Abt Associates Nigeria/PATHS2 Project

Apapo ibisi ni awon orile ede iwo oorun Afirika

Ibisi fun obinrin kan laarin odun meta siwaju iwadi naa

Ghana2008 DHS

5.04.0

5.04.9

Benin2011-12

DHS

Cote d’Ivoire2011-12

DHS

Senegal2010-11

DHS

Sierra Leone2008DHS

Liberia2007DHS

Nigeria2013DHS

Burkina Faso2010DHS

Mali2006DHS

Niger2012DHS

5.1 5.2 5.5 6.0 6.67.6

Bi lilo ilana ifeto somo bibi se gbile si ni elekunjekun

Nigeria15%

Ida ninu ogorun awon obinrin ti o wa ni ile oko lowolowo ti ojo ori won wa laarin odun meedogun si mokandinlaadota

ti won n lo eyikeyi ninu ilana ifeto somo bibi

10-25% >25% <10%

North East3%

North West4%

North Central16%

South West38%

South East29%

South South28%

BCG DPT 3 Polio 3

Bi eto abere ajesara se n lo si

48

2003 NDHS 2008 NDHS 2013 NDHS

5150

21

383529

5439

Ida lona ogorun awon omode ti o je osu mejila si metalelogun ti o gba abere ajesara

Measles All None

364241

132523 27

2129

Iku omode

Isiro se afihan wiwa sile gbogbo ipele iku omode lati odun 2003.

Bi iku omode se n lo siIda lona egberun iku lori awon omo ti a bi laaye

2008 NDHS

Iku omo ti ko pe odun kan

75 69

128

Iku omo ti ko pe odun marun

2013 NDHS

157

201

100

2003 NDHS

Iku omo ti ko pe osu kan

40 3748

NAIJIRIA

Iranlowo lasiko ibimo

*Ida mejidinlogoji ibimo ni o ni

iranlowo osise eto ilera.

Onise ilera agbegbe2%

Oluranlowo noosi/agbebi3%

Dokita10%

Noosi/agbebi25%

Agbebi ibile22%

Ibatan/elomiran23%

Ko si enikankan

13%

Don’t know1%

*Osise eto ilera je dokita, noosi, agbebi, ati oluranlowo noosi/agbebi.

© 2

012

Aki

ntun

de A

kinl

eye-

NU

HRI

, Cou

rtes

y of

Pho

tosh

are