4
YORUBA Heart Guide OKAN ENIYAN Emi o fi ≠kan tuntun fun yin p∂lu, ∏mi tuntun li emi o fi sinu yin, Emi o si mu ≠kan okuta kuro lara yin, Emi o si fi ≠kan ∂ran fun yin. Emi o si fi ∂mi Mi sinu yin. Eskieli 36:26,27. Bi o se n ka iwe ilew≠ yii p∂lu aworan inu r∂, o ni anfani lati ri bi ≠kan r∂ ti ri fun ra r∂. Gba im≠l∂ ∑l≠run laaye lati s≠ bi ≠kan r∂ seri gan fun ≠. Da ∂s∂ r∂ m≠ ki o ma si e iwalaaye ∂s∂ r∂, nitori ≠r≠ ∑l≠run s≠fun wa pe “Bi a wa ba wi pe awa ko ni ∂s∂ awa n tan ara wa j∂, otító kan ko si si ninu wa. Bi awa ba j∂w≠ ∂s∂ wa, olóòótati olododo ni Oun lati dari ∂s∂ wa ji wa, ati lati w∂ wa nu kuro ninu aisododo gbogbo.” 1 Johanu 1:8,9. πe Esu tabi ∑l≠run lo n dari r∂? Iw≠ j∂ eru fun ∂s∂ tabi irans∂ ∑l≠run? Bi ∂s∂ ba n dari aye r∂, ma se s∂, ugb≠n s≠kun si ∑l≠run l≠run. Oun yoo da o ni ide nipas∂ Jesu Kristi ∂ni to wa saye yii lati gba aw≠n ∂l∂s∂ lati s∂ agbara esu ati ∂s∂ lori wa. Oun ni olugbala wa. O wa niwaju ∑l≠run mim≠ to ri gbogboik≠k≠ ero ≠kan to pam≠ ati iwa aye r∂. “Nitorioju r∂ n b∂ ni ipa-≠na eniyan, oun si ri irin r∂ gbogbo, ko si okunkun tabi ojiji iku, ni ibi ti aw≠n onis∂ ∂s∂ yoo gbe sapam≠ si.” Jobu 34:21-22. Ninu AWORAN AK∑K∑ a ri wi pe ta ni o le m≠ ≠kan eniyan? Ko si ohun miiran to j∂ ∂tan to ≠kan eniyan, o j∂ ailera fun un, ti a ko le woosan.” Jere. 17:9. “…Eyi ti o ti inu eniyan jade, eyi I ni ni s≠ eniyan di alaim≠. Nitori lati inu ≠kan eniyan ni ero buburu ti I jade wa, pansaga, agbere, ipaniyan, ojukokoro, iwa buburu, itanj∂, w≠bia, oju buburu, is≠r≠ odi, igberaga, iwere. Lati inu wa ni gbogbo nnkan buburu w≠nyi ti I jade, w≠n a si s≠ eniyan di alaim≠. Mk. 7:20-23. OGONGO n sap∂r∂ igberaga, EWUR∏ n safihan ti aye, iwa buburu, pansaga; ∏L∏D∏ n s≠r≠ ∂s∂ imuti-para ati aj∂ki. IJAPA n safihan ≠l∂, ijafafa si aigb≠ran ati iwa oo. AM∑T∏KUN ∂ranko buburu duro fun ikorira, ibinu ati igbonara. EJO n sap∂r∂ owu jij∂. ∑P∑L∑ n s≠ nipa ∂s∂ iw≠ra ati if∂ owo ti e gbongbo ohun buburu gbogbo. 1 Timotiu 6:10. Satani ni baba eke gbogbo ati aw≠n ti n pur≠. Johanu 8:44. IRAW∑ ni ∂ri ≠kan ∂nik≠≠kan. Ni ibi aworan yii o d≠ti o si buru. OJU ∑L∑RUN ni ohun gbogbo to n l≠ ninu ≠kan. Ko si ohun kan to le pa m≠ kuro ni oju as∂ ina r∂. AH∑N INA KEKERE ti se ina yika ≠kan n e afihan If∂ ∑l≠run to yika ≠kan ∂s∂, ANGELI duro fun ≠r≠ ∑l≠run. ADABA n safihan ∏MI Mim≠. AWORAN KEJI fi ≠kan ironupiwada ≠kan han to b∂r∂ sii wa ∑l≠run. Nibi o b∂r∂ si gb≠ran si ≠r≠ ∑l≠run. ∏mi Mim≠ n tan si I, Im≠l∂ ∑l≠run ti n le gbogbo okunkun l≠ w≠l∂. Angeli mu ida ti I e ≠r≠ DOWNLOAD THE COMPLETE BOOK WITH COLOUR PHOTOS FREE OF CHARGE ONTO YOUR CELL PHONE OR COMPUTER FROM THE WEBSITE www.angp-hb.co.za

YORUBA Heart Guide OKAN ENIYAN - Heart Of Man

  • Upload
    others

  • View
    66

  • Download
    3

Embed Size (px)

Citation preview

Page 1: YORUBA Heart Guide OKAN ENIYAN - Heart Of Man

YORUBA Heart Guide

OKAN ENIYANEmi o fi ≠kan tuntun fun yin p∂lu, ∏mi tuntun li emi o fi sinu yin, Emi o si mu ≠kan okuta kuro lara yin, Emi o si fi ≠kan ∂ran fun yin. Emi o si fi ∂mi Mi sinu yin. Eskieli 36:26,27.Bi o se n ka iwe ilew≠ yii p∂lu aworan inu r∂, o ni anfani lati ri bi ≠kan r∂ ti ri fun ra r∂. Gba im≠l∂ ∑l≠run laaye lati s≠ bi ≠kan r∂ seri gan fun ≠. Da ∂s∂ r∂ m≠ ki o ma si ≤e ≤∂ iwalaaye ∂s∂ r∂, nitori ≠r≠ ∑l≠run s≠fun wa pe “Bi a wa ba wi pe awa ko ni ∂s∂ awa n tan ara wa j∂, otító kan ko si si ninu wa. Bi awa ba j∂w≠ ∂s∂ wa, olóòót∞ ati olododo ni Oun lati dari ∂s∂ wa ji wa, ati lati w∂ wa nu kuro ninu aisododo gbogbo.” 1 Johanu 1:8,9.

πe Esu tabi ∑l≠run lo n dari r∂? Iw≠ j∂ eru fun ∂s∂ tabi irans∂ ∑l≠run? Bi ∂s∂ ba n dari aye r∂, ma se s∂, ≤ugb≠n s≠kun si ∑l≠run l≠run. Oun yoo da o ni ide nipas∂ Jesu Kristi ∂ni to wa saye yii lati gba aw≠n ∂l∂s∂ lati s∂ agbara esu ati ∂s∂ lori wa. Oun ni olugbala wa. O wa niwaju ∑l≠run mim≠ to ri gbogboik≠k≠ ero ≠kan to pam≠ ati iwa aye r∂. “Nitorioju r∂ n b∂ ni ipa-≠na eniyan, oun si ri irin r∂ gbogbo, ko si okunkun tabi ojiji iku, ni ibi ti aw≠n onis∂ ∂s∂ yoo gbe sapam≠ si.” Jobu 34:21-22.

Ninu AWORAN AK∑K∑ a ri wi pe ta ni o le m≠ ≠kan eniyan? Ko si ohun miiran to j∂ ∂tan to ≠kan eniyan, o j∂ ailera fun un, ti a ko le woosan.” Jere. 17:9. “…Eyi ti o ti inu eniyan jade, eyi I ni ni s≠ eniyan di alaim≠. Nitori lati inu ≠kan eniyan ni ero buburu ti I jade wa, pansaga, agbere, ipaniyan, ojukokoro, iwa buburu, itanj∂, w≠bia, oju buburu, is≠r≠ odi, igberaga, iwere. Lati inu wa ni gbogbo nnkan buburu w≠nyi ti I jade, w≠n a si s≠ eniyan di alaim≠. Mk. 7:20-23.

OGONGO n sap∂r∂ igberaga, EWUR∏ n safihan ti aye, iwa buburu, pansaga; ∏L∏D∏ n s≠r≠ ∂s∂ imuti-para ati aj∂ki. IJAPA n safihan ≠l∂, ijafafa si aigb≠ran ati iwa o≤o. AM∑T∏KUN ∂ranko buburu duro fun

ikorira, ibinu ati igbonara. EJO n sap∂r∂ owu jij∂. ∑P∑L∑ n s≠ nipa ∂s∂ iw≠ra ati if∂ owo ti ≤e gbongbo ohun buburu gbogbo.

1 Timotiu 6:10. Satani ni baba eke gbogbo ati aw≠n ti n pur≠. Johanu 8:44. IRAW∑ ni ∂ri ≠kan ∂nik≠≠kan. Ni ibi aworan yii o d≠ti o si buru. OJU ∑L∑RUN ni ohun gbogbo to n l≠ ninu ≠kan. Ko si ohun kan to le pa m≠ kuro ni oju as∂ ina r∂. AH∑N INA KEKERE ti se ina yika ≠kan n ≤e afihan If∂ ∑l≠run to yika ≠kan ∂s∂, ANGELI duro fun ≠r≠ ∑l≠run. ADABA n safihan ∏MI Mim≠.

AWORAN KEJI fi ≠kan ironupiwada ≠kan han to b∂r∂ sii wa ∑l≠run. Nibi o b∂r∂ si gb≠ran si ≠r≠ ∑l≠run. ∏mi Mim≠ n tan si I, Im≠l∂ ∑l≠run ti n le gbogbo okunkun l≠ w≠l∂. Angeli mu ida ti I ≤e ≠r≠

DOWNLOAD THE COMPLETE BOOK WITH COLOUR PHOTOSFREE OF CHARGE

ONTO YOUR CELL PHONE OR COMPUTER FROM THE WEBSITE www.angp-hb.co.za

Page 2: YORUBA Heart Guide OKAN ENIYAN - Heart Of Man

∑l≠run l≠w≠ “to wa laaye to si lagbara, o mu ju idakida oloju meji l≠, o si n gun ni ani titi de pipin ≠kan ati ∂mi niya, ati orikee ati ≠ra inu egungun, oun si ni olum≠ ero inu ati ete ≠kan.” Heb. 4:12. W∂mi li aw∂m≠ kuro ninu aisedeede mi, ki o si w∂ mi nu kuro ninu ∂s∂ mi. Da aya tuntun sinu mi, ∑l≠run; ki o si tun ≠kan diduro sinu mi. Psalm 51:2-10.

AWORAN IK∏TA n fi ≠kan ironupiwada toot≠ han, o ri bi ∂s∂ ≤e tobi to, to si lagbara eyi ti Jesu fi iku lori igi agblebu. O ni ≠kan ti n kabam≠ fun ∂s∂ r∂ ati eyi to banuj∂ lori awon ∂s∂ r∂. “∏b≠ ∑l≠run ni irobinuj∂ ≠kan, irobinuj∂ ati irora aya, ∑l≠run oun ni iw≠ ki yoo gan.” Ps. 51:17. ∏j∂ Jesu Kristi ≠m≠ r∂ n w∂ wa nu kuro ninu ∂s∂ gbogbo.” 1 Johanu 1:7-9. “Emi ni inu didun si gbogbo ∂ni to r∂ ara r∂ sil∂ to si ronupiwada, ∂ni to b∂ru mi to si gb≠ran si Mi.” Isa 66:2. “Pe, bi iw≠ ba fi ∂nu r∂ j∂w≠ Jesu ni Oluwa, ti iw≠ si gbagb≠ li ≠kan r∂ pe ∑l≠run ji dide kuro ninu oku, a o gba ≠ la.” Romu 10:9.

AWORAN ∏K∏RIN n s≠ nipa krist∂ni to ti ri alaafia pipe ati igbala ayeraye nipas∂ irub≠ ∑l≠run wa ati olugbala wa Jesu Kristi ti w≠n ko si sogo ninu ohunkohun, ≤ugb≠n “nipa agbelebu aye di ∂s∂ si mi, emi si di oku si aye.” Gal. 6:14. “Jesu ku lori agbelebuu ki awa p∂lu le di oku si ∂s∂ ati aaye si ododo.” 1 Peter 2:24. A pa wa las∂ “lati maa rin nipa ti ∂mi, ∂yin ki yoo si mu if∂kuf∂ ara s∂.” Gal. 5:16,25. Pup≠ aw≠n to n pe ara w≠n ni krist∂ni, to n gbadura, to n pin ninu ounj∂ al∂ Oluwa, w≠n n k≠rin ∑l≠run, sib∂ nipa iwa ∂s∂ w≠n, w≠n n kan ≠m≠ ∑l≠run m≠ agbelebu l∂ ∂ kan si. Heb. 6:6. Nibi yii a ri apo owo to j∂ ti Judasi, ∂ni to s∂ Jesu, to ta a ni ≠gb≠n owo id∂. Atupa, ∂w≠n abbl j∂ eyi ti aw≠n jagunjagun to mu Jesu g∂g∂ bii ∂l∂w≠n ni oru. Ohun ti w≠n fi n ta t∂t∂ ni ohun ti aw≠n ologun lo lati s∂ keke le as≠ Jesu ti w≠n pin. Psalm 22,18. W≠n gba gbogbor∂ l≠w≠ Jesu. W≠n k≠ oun ti kalara r∂ wi pe “Aw≠n ≠m≠ ogun gun Jesu ni ∂gb∂ ati aya, lojukanaa ∂j∂ ati omi tu jade.” Johanu 19:33-37. B∂∂ niki ∂yin

p∂lu ka ara yin bi oku si ∂s∂, ≤ugb≠n bi alaaye si ∑l≠run ninu Kristi Jesu, ∂ ma≤e j∂ ki ∂s∂ ko j≠ba ninu ara kiku yin, ti ∂ o fi maa gb≠ ti if∂kuf∂∂ r∂. Romu 6:11,12. “Nitori ∂yin ti ku, a si fi iye yin pam≠ p∂lu Kristi ninu ∑l≠run.” Col. 3:3.

AWORAN KARÙN-ÚN n se afihan ≠kan to m≠, ti a w∂ m≠, eyi ta gbala nipa ore-≠f∂ ati aanu ∑l≠run l≠p≠l≠p≠. O ti wa di t∂mpili ∑l≠run toot≠, Ile ∑l≠run, Ti Baba, ∑m≠ ati ti ∏mi Mim≠, g∂g∂ bi Ileri Olu wa Jesu Kristi “Bi ∂nik∂ni ba f∂ran Mi, yoo pa ≠r≠ mi m≠ Baba mi yoo si f∂ran r∂, awa o si t≠ ≠ wa, a o si ≤e ibugba wa pelu r∂.” Johanu 14:23. Dipo ko ma bi ∂s∂ ≠kan r∂ a r∂wa, eyi ti n ≤e igi to n ≤o eso ti ∂mi, g∂g∂ bii if∂, ay≠, alaafia, ir∂l∂, suuru, iwa –p∂l∂, isoore igbagb≠, ikora-∂ni-ni-janu ati iru w≠n ni to ≤e it∂w≠gba, to si t∂ ∑l≠run l≠run ati eniyan. Gal. 5:22,23. Ninu Aworan yii a tun se akiyesi Angeli to farahan. A yan aw≠n Ag∂li lati maa s≠ aw≠n to ba bu ≠la fun ∑l≠run ati lati gba w≠n kuro ninu ewu. Psalm 34:7. Esu p∂lu duro ni tosi ≠kan, o n wa anfaani lati w≠ inu ≠kan naa ti ≤e Ile r∂ atij≠. Nitori naa a gba wa ni iyanju lati wa ni oju ni alakan fi n s≠

2 ATONA YORUBA

FATH

ER SON

GODHOLY SPIRIT

Page 3: YORUBA Heart Guide OKAN ENIYAN - Heart Of Man

ori. “∑ta r∂ Esu, bi i kinnihun ti n ke ramuramu, o n rin ka a kiri, o n wa ∂ni ti yoo paj∂ kiri.” 1 Peter 5:8. “∏yin ko m≠ pe t∂mpili ∑l≠run ni ∂yin n ≤e, ati pe ∏mi ∑l≠run n gbe inu yin.” 1 Korint 3:16; 6:19,20.

AWORAN ÌK∏FÀ n t≠ka ≠kan AP∏YINDA to ba ni ninu j∂, oju kan r∂ b∂r∂ si dì, sú, fihan pe o ti b∂r∂ si tutu, ati pe o b∂r∂ si to ogbe ninu ∂mi loju ≠na kristeni, nigbati oju keji lainitiju n wo kaa kiri lati ni if∂ si aye. Im≠l∂ to wa ninu r∂ ti n di baibai. ∑kan r∂ ko si mura m≠ lati jagun p∂lu Kristi, ko si duro sinsin. Id∂wo yi ka kiri to n gb≠j∂g∂ fun. O si ti le maa l≠ sile ìj≠sìn, to n fi asa ati i≤e aye r∂ si ab∂ isin lati fi boju. Ife ∑l≠run ti tutu ninu ≠kan r∂, iraw≠ ninu ≠kan r∂ ∏ri ≠kan r∂ ti di baibai, ko le fi ay≠ gbe agbelebu m≠, a ko le ki ku ab≠ p∂lu eru wuwo “∏ maa s≠na, kí ∂ si maa gbadura ki ∂ maa baa subu sinu id∂wo. ∏mi n f∂, ≤ugb≠n o ≤e ailera fun ara.” Matiu 26:41. “πugb≠n olododo ni yoo ye nipa igbagb≠, ≤ugb≠n bi o ba fa s∂yin, ≠kan mi ko ni inu didun si.” Heb. 10:38. “Ranti aya Loti.” Lk. 17:32.

AWORAN ÌKÉJE n se afihan ipo ti ap∂hinda eniyan wa. “Bawo

YORUBA ATONA 3

ni aw≠n to ti fi igbagb≠ w≠n sil∂ ≤e le tun wa si ironupiwada? W≠n ti wa ninu im≠l∂ ∑l≠run, W≠n tit≠ ∂bun ≠run wo, ti w≠n si ti di alabapin ∏mi Mim≠.” Heb. 6:4. ∏yin ti ≠kan r∂ yigbe nigba ti ∑l≠run n baa s≠r≠, yoo buru jai nigba ti o ba n gbiyanju lati yi ara r∂ l≠kan pada. Nipa ap∂hinda, Jesu fun ra r∂ s≠ ipo r∂, nigba ti o wi pe “Nigbati ∂mi buburu ba jade ninu eniyan kan, yio rin irin ajo l≠ si oril∂-ede miiran lati wa aaye ti yoo fi sin mi, ti ko ba ri ≠kan, yoo s≠≠ fun ara r∂ pe, Emi o pada sile mi atij≠, yoo pada, yoo si ba ni mim≠ lai ni id≠ti. Osi jade l≠, o tun mu ∂mi meje miiran wa ti o buru ju ara r∂ l≠, w≠n si wa lati maa gbe ib∂ … Eniyan naa wa ni ipo buburu ju ti ib∂r∂ l≠..” Lk. 11:24-26 “Ohun to s∂l∂ si w≠n n safihan owe otit≠ pe Aja tun pada si ebibi r∂ ati ∏l∂d∂ ta ti w∂ m≠ sinu af≠ ninu ∂r∂.” 2 Peter 2:22. πe aworan yii n t≠ka si ipo ti ≠kan r∂ wa? ∑r∂ ≠w≠n, kigbe t≠ ∑l≠run l≠ lati inu ≠kan r∂. “Nitori naa o si le gba w≠n la p∂lu titi de opin, ∂ni to ba t≠ ∑l≠run wa nipa r∂, nitori to n b∂ laaye lati maa b∂b∂ fun w≠n.” Heb. 7:25. “Bi ∂yin ba gb≠ ohun

r∂, ∂ ma ≤e se ≠kan yin le.” Heb. 4:7. “∏ni ta ba n ba wi to n wa ≠run ki, yio parun lojiji, lai si atun ≤e.” Owe 29:1.

AWORAN K∏J∑ n ≤e it≠ka si ≠kan lile ∂l∂s∂ to n sún sise ipinnu p∂lu Jesu Kristi siwaju, to ^ sún m≠ bebe iku. Iku (egungun) de ni aireti ati akoko ti ko f∂. Igbadun ir≠ ti ∂s∂ mu wa ti poora, ipo buburu to ga ati idiyele fun ∂s∂ ni o ni lati doju k≠. Oró ≠run apaadi di ohun to daju fun un. O n f∂ lati gbadura ≤ugb≠n ko le ba ∑l≠run s≠r≠ m≠, ∂ni to ti k≠ if∂ r∂ sil∂ fun ≠j≠ pip∂. Iku ni ere ∂s∂. Romu 6:23. “Ohun ∂ru ni lati subu si ≠w≠ ∑l≠run alaaye.” Heb. 10:31. Ni isa oku (aye oku), owa ninu oro nla. Lk. 16:19-31.

AWORAN K∏SAN-AN duro fun KRISTEINI OLOTIT∑ TO S∏GUN lori irora idanwo ati id∂wo. Nigba ta ba dan an wo niha gbogbo, to duro sinsin dopin, to s∂gun nipa s∂ Jesu Kristi. Satani p∂lu aw≠n ∂mi okunkun r∂ n yi ≠kan onigbagbo ka, lati ≤e ohun ait≠.

Page 4: YORUBA Heart Guide OKAN ENIYAN - Heart Of Man

4 ATONA YORUBA

Okunrin kan to gbe igo waini l≠w≠ kan, o n jo yipo kristi∂ni, o n gbiyanju lati dan-an wo p∂lu if∂ aye to kun fun ir≠ ko ni ipa kankan m≠ tori krist∂ni to ti fi ara r∂ jin, to si ti di oku si ∂s∂ ati ohun aye yii. IRAWO ti ≤e ∂ri ≠kan r∂ m≠l∂ to si tan. APO OWO TO SI SIL∏ fi han pe ki I ≤e ≠kan r∂ nikan, bi ko≤e p∂lu owo r∂ lo fi jin fun ∑l≠run. AKARA ati ∏JA fihan pe o n gbe Igbe-Aye to m≠ ati ikora∂ninijanu. Ko fi ≠ti lile ba ara r∂ j∂. IWE TO SI SIL∏ tum≠ si pe Bibeli j∂ iwe to si sil∂ fun un, to n ka, to si n ≤e asaro ninu r∂ lojojum≠. “Ta ni yio ha ya wa kuro ninu if∂ Kristi? Ip≠nju ni tabi inunibini, tabi iyan tabi ihoho tabi ewu tabi ida? G∂g∂ bi a ti k≠ ≠ pe Nitori r∂ ni a se n pa wa ku ni gbogbo ≠j≠, a n ka wa si bi aguntan fun pipa. πugb≠n ninu gbogbo nnkan w≠nyi, awa ju ∂ni to s∂gun l≠, nipa ∂ni to f∂ wa.” Romu 8:35-37. “∏nik∂ni to ba n gbe inu r∂ ki I d∂s∂.” 1 Johanu 3:6-10. “Nitori olukuluku ∂ni ti a ba bi nipa ti ∑l≠run o s∂gun aye, eyi si ni is∂gun ti o s∂gun aye, a ni igbagb≠ wa.” 1 Johanu 5:4,5. “πugb≠n ninu gbogbo nnkan w≠nyi awa ju ∂ni ti o s∂gun l≠ nipa ∂ni ti o f∂ wa.” Romu 8:37.

NINU AWORAN K∏WAA a o ri pe eniyan to ti gbe aye to si ti rin p∂lu ∑l≠run ko le b∂ru Iku. Nigba ti akoko ba to fun lati ku, inu didun ni yio fi l≠ g∂g∂ bi Aposteli Paul ti wi “≤ugb≠n emi n b∂ ni iyemeji mo ni if∂ lati l≠ ati lati wa l≠d≠ Kristi; nitori o dara pup≠ ju.” Filipi 1:23. “Ninu ile Baba ≠p≠l≠p≠ ibugbe li o wa, iba ma ≤e b∂∂, emi iba ti s≠ fun yin. Emi o tun pada wa, pe nibi ti emi gbe wa, ki ∂yin le wa nib∂ p∂lu.” Johanu 14:1-4. “Ohun ti oju ko ri, ti eti ko gb≠, ti ko si w≠ ≠kan eniyan l≠, ohun w≠n ni ti ∑l≠run ti pese sil∂ fun aw≠n to f∂ ∂.” 1 Korinti 2:9. “Alabukun fun ni aw≠n oku to ku nipa ti Oluwa lati ihin l≠; B∂∂ ni ∏mi wi, ki w≠n ki o le sin mi kuro ninu laalaa w≠n, nitori is∂ w≠n n t≠ w≠n l∂hin.” Ifihan 14:13. “Oluwa wi fun pe, o ≤eun iw≠ ≠m≠-≠d≠ rere ati olooot≠.” Matt. 25:21.

∏ J∏ KA GBADURA∑l≠run mo wa s≠d≠ r∂ p∂lu ∂s∂ mi ati ≠kan buburu mi. Emi ko le e yi pada. Gba ≠kan mi bo ti ri, Da ≠kan mim≠ sinu mi. ∑l≠run fi ∂mi Mim≠ r∂ kun mi ati if∂ r∂. Amin.

Kindly write to us if you are able to assist us with further translations of our free Gospel literature, informing us of the language into which you could translate this Gospel literature. Your assistance would be appreciated.

If you have found salvation in Christ, or have been otherwise blessed through our Gospel literature, please let us know. We would like to thank God with you, and remember you further in our prayers.

For free Gospel literature, books and tracts in over 540 languages, write to:

E-MAIL: [email protected] NATIONS GOSPEL PUBLISHERSP.O. Box 2191, PRETORIA, 0001, R.S.A.

(A Gospel Literature Mission financed by donations)(Reg. No. 1961/001798/08)